Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Tope Osoba se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún métàlélógbò (33) pèlú...

Temitope Osoba tí gbogbo ènìyàn mò sí Tope Osoba jé òsèré orílè èdè Nìjíríà tí ó sì tún jé olùko eré, won bí i ní ojó kejì osù kejìlá, odún 1985. Ó jé jé akékòó jáde ilé-èkó gíga ifáfitì Olabisi...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Bánà Omo Egbé APC tí ó n lo fún Gómìnà ìpínlè Kwara ni won lè sí iwájú...

Bánà Omo Egbé APC tí ó n lo fún Gómìnà ìpínlè Kwara ni won lè sí iwájú agboolé àwon Saraki. Ìròyìn kàyéfì… Omo egbé APC tí a mò sí Abdulrasaq Abdulrahman, tí ó n díjé fún ipò Gómìnà ìpínlè Kwara ti se...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Gómìnà ìpínlè Osun tí a sí Oyetola gba àwon èèyàn là nínú ìjàmbá okò tí ó...

Ókéré jù èèyàn tí ó kojá néjìlá ni ó fara pa nínú ìjàmbá tí ô selè ní òpópónà Ibadan lo sí Èkó sùgbón tí Gómìnà Oyetola ti gba wón kalè. Ògbéni Isiaka Oyetola náà n lo sí èkó ni ojó náà kí ó tó di wípé...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Mi ò le fé okùnrin tí kò bá le bámi sùn fún wákàtí méjìlá sí méèdógún.

Mi ò le fé okùnrin tí kò bá le bámi sùn fún wákàtí méjìlá sí méèdógún. Arábìnrin kan tí a kò fi taratara mo orúko rè súgbón tí kò le jú omo odún méèdógún sí ogbòn kan ni ó so wípé òun kò le fé okùnrin...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àwon tí ó n gbélè sunkún síta fún ìrànlówó nígbà tí àwon adigunjalè jàwón...

Àwon olùgbé Opolo ní Yenagoa ìpínlè Bayelsa ni ìbèrùbojo ti gba okàn won léyìn tí àwon adigunjalè jà won lólè tán. Gégé bí ìròyìn se so, àwon olè yí kojá ogbòn tí won sì gbé àwon ohun ìjà olóró lówó...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Awon Aworan Iyẹdọla Iyaaṣa

Ọpẹ lọwọ Edua fun aṣeyọri iwure ta ṣe, iroko a sẹrọ fun gbogbo wa o, awọn alaṣeku a bawa ṣe, Edua a mu ibeere wa ṣẹ, aṣẹ.IYẸDỌLA_IYAAṢA! ỌKIN ỌLỌJA ẸIYẸ!!!

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Olamide, Adekunle Gold, Praiz, Do2dtun àti Wizkid ní ibi OLIC 5.

Olamide, Adekunle Gold, Praiz, Do2dtun àti Wizkid ní ibi OLIC 5. Nse ni ó dàbí eni wípé àjòdún odoodún tí a mò sí OLIC 5 ti Olamide àti Wizkid papò sí ojó kan náà, tí a mò sí ojó àná, orúko àríyá...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Biodun Okeowo pín àwòrán tí ó rewà láti se ayeye odún Kérésì.

Biodun Okeowo pín àwòrán tí ó rewà láti se ayeye odún Kérésì. Gbajúgbajà Òsèré bìrin náà tí ólúwa fún ní ewà àti ara tí ó wuyì , orúko rè a máa jé Biodun Okeowo, ìnagije rè a sì máa jé Omo Butty ti fi...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Tonto Dikeh sòrò nípa arákùnrin tí ó n bá àyànfé ìyàwó rè jà níbi ìpéjo àríyà...

Tonto Dikeh sòrò nípa arákùnrin tí ó n bá àyànfé ìyàwó rè jà níbi ìpéjo àríyà ti Burna Boy. Gbajúgbajà Òsèré obìnrin tí a mò sí Tonto Dikeh, ti pín èrò rè sí orí èro ayélujára látàrí fídíò tí won pín...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Owó ti te àwon gbómogbómo àti àwon Adigunjalè tí ó n da Adamawa àti èèyàn ibè...

Owó ti te àwon gbómogbómo àti àwon Adigunjalè tí ó n da Adamawa àti èèyàn ibè láàmú. Ogbóntarigì gbómogbómo àti àwon adigunjalè tí ó n da àwon èèyàn ati awon olùgbé ìpínlè Adamawa láàmú ni owó àwon...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Alàgbà Nathaniel Ognonanaya Ugwu ni ìsèlè ìjàmbá Okò selè sí.

Alàgbà Nathaniel Ognonanaya Ugwu ni ìsèlè ìjàmbá Okò selè sí. Alàgbà kan ní ìjo Catholic se oríre wípé èmi rè sì wà láyé nípa tí ikú ti fo orí rè kojá nínu ìjàmbá okò tí ó ní. Gégé bí ìròyìn se so,...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àwon èrò àti ò n wò ran pariwo “Ó tó gé olè” fún Bukola Saraki àti olùdíje...

Àwon èrò àti ò n wò ran pariwo “Ó tó gé olè” fún Bukola Saraki àti olùdíje fún ilé-ìgbìmò Asòfin ti egbé PDP. Báyìí ni àwon èrò àti àwon ará ìlú se pariwo mó Ààre ilé-ìgbìmò Asòfin àti olùdíje...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Gideon Okeke àti Chidera Udueze se ayeye ìgbéyàwó ìbílè won

Òsèré okùnrin tí gbogbo èèyàn Gideon Okeke ti se ìgbéyàwó ìbílè tàbí ti àbáláyé rè pèlú òkín láwùjo gbogbo eye, è yun ún ìyàwó rè tí ó rewà, orúko ìyàwó rè náà a máa jé chidera. Eléyìí kíì se iró tàbí...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Sola Sobowale dàbí egbin bínú aso tí ó wo lo síbi ìfilólè eré orí ìtàgé tí...

Sola Sobowale dàbí egbin bínú aso tí ó wo lo síbi ìfilólè eré orí ìtàgé tí àkolé rè n jé “King of Boys. Ògbóntarìgì tí ó tún jé gbajúgbajà òsèré tí gbogbo èèyàn mò sí Sola Sobowale, wo aso aláràbarà...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Okò bògònì tí a mò sí Bentley ti Linda Ikeji rà fún omo rè tí orúko rè n jé...

Okò bògònì tí a mò sí Bentley ti Linda Ikeji rà fún omo rè tí orúko rè n jé Jayce Jeremi, ti dé sí ìlú èkó. Linda Ikeji ti pin sí orí èro ayélujára láti fi hàn wípé okò tí òhun se ìlérí fún omo òhun...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìmú wo egbé òkùnkùn ti ó selè ní ìjoba ìbílè Obanliku ní Ìpínlè Cross River...

Ìmú wo egbé òkùnkùn ti ó selè ní ìjoba ìbílè Obanliku ní Ìpínlè Cross River ti mú èmí eni tí won fé mú wo egbé náà lo ní ojó ketàdínl’ógbòn osù òpe odún 2018. Orúko arákùnrin náà a máa jé Miracle....

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Purity Okojie se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún méfà (6) ní àná:...

Akoni àti ogbóntàrigì òsèré obìnrin, tí a mò sí Mercy Johnson Okojie, tí ó fé omo oba Odi Okojie tí ó sì bí omo méta, Okúnrin kan obìnrin méjì. Mercy Johnson ti se ayeye ojó ìbí fún àkóbí rè, orúko...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

E jowo e ran wa leti isele inu aworan yii

Eyin ara Abule, e ba ni se akiyesi aworan yii daadaa. Se kii se pe ogbeni yii fee yin ibon AK47 mo obinrin yii lapa ni?  E jowo e ran wa leti isele inu aworan yii, asiko wo ni isele yii waye? Agbegbe...

View Article

Àkóṣe Ọ̀ràngún Méjì

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iná awerepèpè, a ó lọ̀ ọ́ kúnná dáadáa, a ó wà ṣa tí yóó gbẹ dáadáa. Ọ̀ràngún méjì ni a ó tẹ̀ ẹ́. A ó pe Ifá sí, a ó fi ṣín gbẹ́rẹ́ la orí já. A ó wà á fi ẹbu Ifá náà rá àwọn ojú gbẹ́rẹ́...

View Article

ÌMỌ́DÒYE

An Akodi Orisa SculptureIle Ife, Nigeria January 2019Artist: Moyo Okediji

View Article
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live