Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 1429

Biodun Okeowo pín àwòrán tí ó rewà láti se ayeye odún Kérésì.

$
0
0

Biodun Okeowo pín àwòrán tí ó rewà láti se ayeye odún Kérésì.
Gbajúgbajà Òsèré bìrin náà tí ólúwa fún ní ewà àti ara tí ó wuyì , orúko rè a máa jé Biodun Okeowo, ìnagije rè a sì máa jé Omo Butty ti fi ewà àti ara tí ó wuyi yí hàn nínú àwòrán tuntun tí ó sèsè yà. Ó ya àwòrán yí láti fi se ayeye odún Keresi àti ti ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún métadínlàádóta (47) ní ìjeta . E wo àwòrán ní ìsàlè


Viewing all articles
Browse latest Browse all 1429

Trending Articles