Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Olorì Basirat tí ó pé odún mókàndínlógún ni ojó mélòó séyìn ya àwon àwòrán tí...

Olorì oba àti ìyá ìbejì ni a gbó wípé ó máa n dá oba lóhùn láàfin àti wípé òhun ni ó máa n pèsè gbogbo nkan tí Kábìèsí fé láàfin àti ní orí èro ayélujára. A gbó wípé kò sí ibi náà tí e ó ti ri Aláàfin...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Olódùmarè mà tóbi lóba ooo.

Olódùmarè mà tóbi lóba ooo. Kíni olórun olódúmarè kò le se tán, Olódùmarè tó dá ayé òhun òrun tí ó sì so òrò sí órìlè ayé, òrò náà á máa jé Ifá tí ó fi rán òrúnmìlà baba àgbónìrègún. Òdú ìfá ni ó sì n...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

KÁDÀRÁ Ò GBÓÒGÙN

Adáni wáyé ti dáni sáyé ná. Káwayé máyà tó sayé dàwáàlọ. Òréré layé kò see wò tán. Àyàfi ká gba kádàrá lókù. Kádàrá ò seé kọ̀ láìgbà. Ádíá f’ẹ́ja tó f’ibú...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Tonto Dikeh se tán láti se isé abe láti tún ara rè dá.

Tonto Dikeh se tán láti se isé abe láti tún ara rè dá. Gbajúgbajà àti ìlú mòóká òsèré tí a mò sí ìyá ìjo, Tonto Dikeh, ti gbe lo sí orí èro ayélujára Ínsítágírámú láti jé kí ámò wípé nse ni ó dàbí eni...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àwòrán omo odún mókàndínlógún (19) tí won mú pèlú orísirísi èyà ara ní Awka.

Gégé bí ìròyìn se so, won ti fi ìgò gún omo odún mókàndínlógún (19) yánmayànma látàrí àwon èyà ara tí won bá ní owó rè, won bá omoníka àti ojú ara omo odún mérin okùnrin ní Awka, ìpínlè Anambra. Afura...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó olùwòsàn tí ó tún lóyún sínú àti oko rè tó jé...

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó olùwòsàn tí ó tún lóyún sínú àti oko rè tó jé Engineer. Olúwòsàn tí ó tún lóyún sínú àti oko rè tí ó jé Engineer ti pín àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won. Arábìnrin yí...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Cee C jáde pèlú Uriel àti Craze Clown ní Dubai .

Cee C jáde pèlú Uriel àti Craze Clown ní Dubai . Àwon ará ilé BBnaija télè, Cee C àti Uriel ya àwòrán papò pélù Craze Crown ní orílè èdè Dubai. E wo àwòrán àwon àwom métèta tí ó rewà púpò jù.

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Mo ti rí eni náà” Burna Boy pín àwòrán tí ó rewà pèlú arábìnrin arewà kan.

“Mo ti rí eni náà” Burna Boy pín àwòrán tí ó rewà pèlú arábìnrin arewà kan. Gbajúgbajà àti ogbóntarìgì olórin tí a mò sí Burna Boy nse ni ó dàbí eni wípé ó ti rí àyànfé, ó pín àwòrán tí won dì mó ara...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Babajide Sanwoolu àti Obafemi Hamzat pàdé àwon ìlúmòóká Òsèré.

Babajide Sanwoolu àti Obafemi Hamzat pàdé àwon ìlúmòóká Òsèré. Omo egbé APC tí won yàn láti díje fún ipò Gómìnà ní ìpínlè Eko, tí a mò sí Babajide Sanwoolu àti akegbé rè tí òun a máa jé, Omòwé Obafemi...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ògbóntarìgì Adigunjalè tí ó n dà àwon ará Delta láàmú ni owó ti tè.

Ògbóntarìgì Adigunjalè tí ó n dà àwon ará Delta láàmú ni owó ti tè. Ògbólògbó adigunjalè ní òrò won ti já sí òfo látàrí àì jé kí àwon èèyàn ní ìfòkànbalè ní ìpínlè Delta. Àwon adigunjalè méjì tí ó n da...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Kí ni ojú ò rírí, kárí ká f’ojú fò lópò. Njé Eléhà ninèyí tàbí Egúngún?.

Òrò náà só síni lénu ó tún buyò si, àbí bí èèyàn yóò bá jé òsákálá kí ó jé Òsákálá bí yóò sì jé Òsokolo kí ó ké Òsokolo, èwo ni òsákálásokolo. Èyí èèyàn sé Eléhà ni a ó pe eléyìí ni àbí Egúngún?....

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Goodluck Ebele Jonathan se ayeye odún mókànlélógóta (61) ojó ìbí rè ní èní.

Goodluck Ebele Azikiwe Jonathan GCFR GCON tí won bí ní ogún’jó osù Belu ní odún 1957, tí ó jé olósèlú ní orílè èdè Nìjíríà tí ó sì sin ìlú gégé bíi Ààre orílè èdè Nìjíríà láti odún 2010-2015. Kí ó tó...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Tobi Bakre ya àwòrán pèlú Rita Dominic, Lolu, Bovi àti Ebuka.

Ará ilé BBNaija télè tí ó sì jé àyànfé òpò ènìyàn tí a mò sí Tobi Bakre lo sì orí èro ayélujára rè tí ó n jé Insítágírámù láti pín àwòrán òhun àti àwon ènîyàn pàtàkì bíi Rita Dominic, Lolu, Bovi àti...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Arábìnrin omo odún méèdógbòn, tí ó tún jé a fi ewà s’oge, Chidimma Leilani...

,Chidimma Leilani Aaron, omo odún méèdógbòn láti ìpínlè Enugu ti tayo àwon métàdínlógún (17) tí won jo díje fún omidan àkókó ní orílè èdè Nìjíríà ti odún yí. O di eni kejìlélógójì tí yóò gba àmì èye yí...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àwon àwòrán tí ó rewà tí Lota Chukwu fi se ayeye ojó ìbí rè nígbá tí ó pé omo...

Àwon àwòrán tí ó rewà tí Lota Chukwu fi se ayeye ojó ìbí rè nígbá tí ó pé omo odún mókàndínlógbòn (29). Gbajúgbajà arewà òsèré orílè èdè Nìjíríà tí ó n jé Lota Chukwu se ayeye odún mókàndínlógbon ojó...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Olùsò àgùntàn tí a mò sí pásítò Adeboye tí ó jé olórí àwon omo léyìn Jésù ti...

Olórí àwon olùfokànsìn àti omo léyì jésù ti Ìjo àwon RCCG, gbogbo àgbáyé, Pásítò E.A Adeboye fún àwon akékòó tí won sèsè gboyè gégé bíi adájó mérin nínú ìjo rè ní àgbàlá HALL OF MERCY, Bwari ní ìpínlè...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Mr Harri se ìgbéyawó pèlú ohun èlò orin tí a mò sí guitar ní ìpínlè Eko.

Arákùnrin kan ní orílè èdè Nìjíríà ti ya òpò èyan lénu látàrí sése ìgbéyàwó pèlú ohun èlò orin tí a mò sí guitar rè. Tí e bá rò wípé e ti ri tán , eléyìí tún ya ni lénu ò. Harri best ti pín sí orí èro...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Arákùnrin tí ó n se yahoo ni ó ti ya wèrè nígbá tí bàbá eè kú tán ní ìlú Benin.

Kàyéfì nlá ni ó jé nígbà tí Arákùnrin kan ya wèrè ní ìlú Benin ní ìpínlè Edo. Gégé bí ìròyìn se so, òdókùnrin yí ni won fi èsùn kàn wípé isé kí á máa fi èro gbáni ni ó n se tí a mò sí Yahoo ni ó n se....

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àwon Jagunjagun tí a mò sí Soldier ti pa ìko àwon Boko Haram ní Arege, Borno,...

Two Ikò Boko Haram ti fi ojú winá ogun won sì ti bá ogún lo, tí ojú won sì rí méwàá ni ojó kejìlélógbòn osù kokànlá odún 2018 nígbà tí won tún fé se bí ìse won ní Arege ní ìjoba ìbílè Mobbar ní ìpínlè...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àwòrán télè ti Leo Babarinde Dasilva nígbà tí ó wà ní omo àgbákórùn.

Àwòrán télè ti Leo Babarinde Dasilva nígbà tí ó wà ní omo àgbákórùn. Ní àná tí se ojóbò tí àwon eléyìbó n pè ni Thursday, won ni kí àwon wo èyìn wò. Ará ilé BBNaija télè tí a mò sí Leo Babarinde...

View Article
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live