Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live

Àwòrán tí Tonto Dikeh àti Halima Abubakar yà tí won sì rewà nínú àwòrán náà.

  Òsèrè orí ìtàgé, Tonto Dikeh gbe lo sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà yí tí òun àti òré rè tímótímó , òsèré Halima Abubakar yà.

View Article


Nnamdi Mpiti tí ó jé akunjú (make up artist) pín àwòrán yí .

   E má jé kí èrù bà wá . Kíkùn lásán ni , àti wípé èjè iró ni ó wà níbè “.

View Article


Ajé omo Olókun.

   Òrìsà ni olókun jé, a gbó wípé òun ni ó bí ajé, ó tún jé òrìsà orò àti ti ìsàlè òkun. Olókun ni ó n darí omi ó sì ní àse l’órí gbogbo ìsèdá inú omi . Olókun máa n fún ni ní orò , èmí gígùn abbl. Ajé...

View Article

Àwòrán ayeye ìsìnkú Obi Madubogwu.

Àwòrán ayeye ìsìnkú Obi Madubogwu. Akoni òsèré , Obi Madubogwu tí ó kú ní ojó kejìdínló’gbòn osù kejo ( 28/8) nígbà tí ó jèrora ìtò súgà fún bí odún díè séyìn ni won ti sin sí ìlú rè ní Ogidi ìpínlè...

View Article

Àwòrán ayeye ìsìnkú Obi Madubogwu.

  Akoni òsèré , Obi Madubogwu tí ó kú ní ojó kejìdínló’gbòn osù kejo ( 28/8) nígbà tí ó jèrora ìtò súgà fún bí odún díè séyìn ni won ti sin sí ìlú rè ní Ogidi ìpínlè Anambra. Gbajúgbajà òsèré , Obi...

View Article


Laura Ikeji Kanu tún yo ní àrà òtò.

  Onísòwò aso àti olù gbé eré jáde, Laura Ikeji gbé lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán tí ó ya ni lénu yí.

View Article

E wo ejò tí aládùúgbò mi pa, e jò wó kíni orúko rè.

   Aládùúgbò mi ló pa ejò nlá yí ní kùtùkùtù òwúrò àná … Oúnje ti se.

View Article

Òdóbìnrin ni ó ya àwòrán orúko Runtown gangan sí ìdí rè.

    Níbáyìí, ojú wo ni òrékùnrin rè ma fi wò ó tí ó bá rí ìdí òdóbìnrin yí?. Àwòrán tí ó ti gba èro ayélujára kan ni ti obìnrin tí ó ko orúko Runtown gangan sí ìdí rè. Olórin ìgbàlódé kan tí ó n jé...

View Article


À n yan Àntà ( alligator ) tí a pa nínú oko ìresì wa.

   Ìsinmi tòtè yí mà yàtà gan o, ó ti è ti dùn jù …járá oko yí mà da gan ni oo . Àwòrán obè aláta yéríyérí n bò láìpé.

View Article


Ààre Buhari lo rí àwon omo egbé CAN ní ilé ìgbìmò ní ìlú Abuja.

   Ààre Muhammadu Buhari ti lo rí àwon omo egbé Christian Association of Nigeria (CAN ) ní ilé ìgbìmò ní ìlú Abuja.

View Article

Odunlade Adekola ti parí ìdánwò è ní UNILAG.

   Gégé bí ó ti pin sí orí èro ayélujára (Instagram). ” Nígbà tí o bá parí ìdánwò, tí o wá n padá li sí ilé , tí o wá kó sínú súnkere fàkere oko, wà sà ya àwòrán, mo kí ara mi àti gbogbo akékòó ilé...

View Article

Skolopad wo aso tí ó fi sósèjì se lo sí ibi láti gba àmì èye South African...

   Àwòrán tí ó gba èro ayélujára kan ti àmì èye south African Feather ti odún yi ni ìmúra àwon èèyàn kò bójúmu rárá. Olórin kan ní South African “Skolopad” wo aso tí ó kún fún sósèjì àti àpò èédú fún...

View Article

Àwòrán tí ó ti pé ti Fela Kuti àti Femi Falana, agbejórò rè .

Àwòrán ògbó-n-ta-rì-gì olórin ní orílè èdè Nàíjíríà, Fela Anikulapo kuti àti agbejórò rè. Gbajúgbajà agbejórò tí ó tún jé bàbá ìlúmòóká olórin Falz d bahdguy ògbéni Femi Falana àti bàbá Beko Ransom...

View Article


Yomi Fabiyi ni Eniola Omoshalewa Eunice fi èsùn ìbálòpò kàn.

   Ogún-l’ógbòn àwon eléré orí ìtàgé ni ó n fi tipátipá béèrè ìbálòpò lówó àwon èèyàn láti le jékí won hàn nínú eré ti orílè èdè Nàíjíríà (Nollywood) gégé bí ìyá kan àti eni tí ìsèlè yí selè sí se fi...

View Article

E wo bí olùyà yí se ya àwòrán Teckno.

   Bí mo se ri ní orí èro ayélujára (Instagram), mi ò ti è mo ohun tí mo fé so, sé Techno sì ma san owó èyí bí.

View Article


Won gbìmò láti da ilé mi wó, Dino Melaye se béè fún Yahaya Bello.

   Asojú ilé ìgbìmò asòfin Melaye ti tako Gómìnà ìpínlè Kogi Yahaya Bello tí ó gbèrò láti wó ilé rè ní ìpínlè Kogi. E kàá dáadáa.

View Article

D’banj lo kí asojú ilé ìgbìmò asòfin Dino Melaye .

   D’banj lo kí asojú ilé ìgbìmò asòfin ni ó pín àwòrán yí “koko master náà ni”.

View Article


Ejò sèbé tí mo won pa ní Ofoni Sagbama ní ìpínlè Bayelsa .

Sèbé nlá ni won pa ní agbègbè Ofoni ní ìjoba ìbílè Sagbama ní ìpínlè Bayelsa . E wo bí won se ge fún obè aláta yéríyérí.

View Article

Isé abe tí ó bùáyà, Hushpuppi káàbámò lábé abe , ó sì gba àwon èèyàn n’ímòràn.

   Léyìn isé abe ; Hushpuppi káàbámò, ó sì gba àwon èèyàn n’ímòràn.

View Article

Tiwa Savage gbégbà orókè níbi àmì èye AFRIMA 2017 tí ó sì gba èye náà mó Yemi...

    Òdóbìnrin olórin àkókó ní ikò Marvins , Tiwa Savage gbé igbá orókè ní ibi àmì èye AFRIMA ti odún yí gégé obìnrin àkókó ní ikò adúláwò ti odún yí. Tiwa Savage pa Yemi Alade, Aramide àti Seyi Shey...

View Article
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live