Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live

Ìmúra Nana Akua Addo fún AFRIMA ti odún yí.

   Òsèré orílè èdè Ghana , Nana Akua Addo ya ni lénu pèlú ìmúra rè lo sí AFRIMA odún yí.

View Article


Ebube Nwagbo fi enu ko eja nlá tí ó n jé Dolphin ní Dubai fún ìsinmi.

Òsèré Ebube Nwagbo tí ó wà ní ìsinmi lówólówó ní Dubai ti pin sí orí èro ayélujára (Instagram) àwòrán aso ìwè rè pèlú bí ó se n wè l’ódò àti eja nlá tí ó n jé Dolphin .

View Article


Jackie Appiah dàbí egbin nínú aso ìbílè tí ó wò.

   Òsèré orílè èdè Ghana, Jackie Appiah, èyí rewà ju kí èèyàn fi ojú paáré lo, òsèré yí ló pin sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà yí níbi tíó ti wo aso ìbílè tí a mò sí Ankara.

View Article

Wizkid ni ó gbé igbá orókè gégé bi okùnrin àkókó ní bi àmì èye AFRIMA ti odún...

Wizkid pa Davido, Techno àti àwon míràn tí ó wá fún àmì èye AFRIMA ti odún yí láyò. Wizkid gba èbùn fún orin rè ” Come closer ” tí ó ko pèlú Drake.

View Article

Ó ye kí ó se ìgbéyàwó ní ojó kejì osù kejìlá odún yí (2nd of December) sùgbón...

Gégé bí ò n lò èro ayélujára (Facebook)se so, odókùnrin yí ye kí ó se ìgbéyàwó ni osù kejìlá sùgbón ó ti di olóògbé. Ó kú nínú ìjàmbá pèlú àwon tí ó kùn rè. Kí olórun te sí aféfé rere. Kí á sì má rí...

View Article


Cristiano Ronaldo àti Georgina Rodriguez kí omobìnrin káàbò, Alana Martina .

   Cristiano Ronaldo ti kí omo rè kerin káàbò, Alana Martina ni orúko rè. E kú oríre Ooo.

View Article

Ódára kí èèyàn San ìdàméwàá, D’banj ni ó so béè .

D’banj pín èróngbà rè nípa ìdàméwàá. E jè rí, àwon omo Nàíjíríà ti da l’óhùn bí ó ti yé.

View Article

Omodé yìí mà ní opolo oo.

Omokùnrin odún méwàá (10yrs) yí láti ìpínlè Anambrah ní orílè èdè Nàíjíríà , òun ni ó kó ilé yí orúko rè ni Chinecherewu. Mi ò le fun ní owó lásán ” ó n’ílò kí gbogbo ayé rí èyí.

View Article


Àwòrán olópàá tí ó n só Afárá Apogbon (Apogbon Bridge).

     Wón ti so síwájú télè wípé àwon olópàá Nàíjíríà n sisé takuntakun láti só agbègbè Apogbon bridge tí a mò fún àwon dánàdánà.

View Article


Ay lo kí Gómìnà Okorocha , ère ti e náà n bò lónà, àwon olólùfé rè ni ó so béè.

   Báyìí ni adérìnpòsónú AY tí ó sèsè dé láti Dubai fún ìsinmi pín àwòrán òun àti Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha nígbà tí ó lo ki n’ílé, tí àwon olólùfé rè sì so wípé ère ti è náà kò ní pé dé…Èrín...

View Article

Akpororo àti ìyàwó rè Josephine Ijeoma Onuabughuchi se ayeye odún kejì...

Adérìnpòsónú, Akpororo àti ìyàwó rè Josephine se ayeye odún kejì ìgbéyàwó won.  

View Article

Ìjàmbá okò tírélà tí ó selè tí ó sì se òpò èèyàn lese ní Gombe.

    Èyí ni ìsèlè tí ó selè láìpé ní ojó kejìlá osù kokànlá odún yí ní Gombe ní ìpínlè Gombe tí tírélà fà . lóòtó kò sí eni tí ó kú, sùgbón òpò ni ó se Lése gan. A gbàdúrà kí elédùà mú won lára dá.

View Article

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí won yà nínú omi adágún.

Odára àbí kò dára?

View Article


Ajá mi , pitbull pa Àntà tí ó n sólé ,obè ti délè oo.

Èrín pa mí, ajá mi, pitbull pa á lónìí , ta ló fé?

View Article

Sandra Okagbue ya orúko flavour “Chinedu” sí owó rè .

   Ìyá omo olórin flavour, Sandra tàtúù orúko rè “Chinedu” sí apá .

View Article


Regina Daniel rewà ó sì dàbí àgbàlagbà níbi àwòrán tuntun tí ó sèsè yà.

  Òdóbìnrin òsèré yí, Regina Daniel ti gbe lo sí orí ìtàn èro ayélujára (insta-stories) láti pín àwòrán tí ó ti yàtò yí.

View Article

Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.

Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.

View Article


Gómìnà Obaseki se ayeye odún kan tí ó ti dé ipò, Akeredolu àti Amaechi náà sì...

    Gómìnà ìpínlè Ondo, Akeredolu lo bá Gómìnà ìpínlè Edo se àjoyò odún kan tí ó dé ipò ní pápá Samuel Ogbemedia, Benin city.  

View Article

Destiny Etiko wo sòkòtò bénbé pèlú aso yí ó ba mu.

Òsèré Nàíjíríà tí a mò sí Etiko Destiny ti jáde láì wo Kómú. Òsèré yí wá gbe lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán tí kò wo Kómú yí.

View Article

Ère Nana Akufo- Addo ni Rochas Okorocha fé sín ní Imo.

   Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha ti se tán láti sín ère ààre Nana Addo ti Ghana ní Owerri nígbà tí ó ti sí ère ti ààre Ellen Sirleaf ti Laberia àti Zuma ti South Africa . Ère náà ti férè se tán...

View Article
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live