Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 1429

Àwòrán tí ó ti pé ti Fela Kuti àti Femi Falana, agbejórò rè .

$
0
0

Àwòrán ògbó-n-ta-rì-gì olórin ní orílè èdè Nàíjíríà, Fela Anikulapo kuti àti agbejórò rè. Gbajúgbajà agbejórò tí ó tún jé bàbá ìlúmòóká olórin Falz d bahdguy ògbéni Femi Falana àti bàbá Beko Ransom Kuti .

Mo gbàgbó wípé òrò ilé-ejó ni àwon akoni yí nso, àbí béè kó ni.


Viewing all articles
Browse latest Browse all 1429

Trending Articles