Òrékùnrin mi ń bínú sími.
E jòwó, mo fé àmòràn lórí ohun tí ó ye kí n se, osù kewàá rèé tí mo ti mo Òrékùnrin mi, a sì ní ìfé ara wa, sùgbón Òrébìnrin rè télè sì ń dàá láàmú, èyí sì ń jé kí n jowú. No wá gbèrò láti sí èro...
View ArticleOmokùnrin kan tí orúko rè ńjé Charlyboy subú lulè nígbà tí won ń se àtakò...
Àmóhùnmáwòrán Channels ti pín fídíò tí ó se àfihàn omokùnrin kan tí ó ń jé Charlyboy nígbà tí ó subú lulè nígbà tí won ń tako Buhari lówó ní ìlú Abuja láàárò òní. Àwon Agbófinró fín tajútajú àti omi...
View ArticleMusa Musa, olóòpá tí ó fó ilé Jonathan.
Àwon Agbófinró ti rí àwòrán olóòpá kan tí ó jé atónà fún àwon ìgárá olóshà tí ó fó ilé Ààre télè Goodluck Jonathan ní Gwarimpa Abuja. Musa tí a gbé lo sí ilé-ejó gíga díè (magistrate) ní ojó ìségun tí...
View ArticleOdu ifa IROSUN OSE/ALAJE
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isinmi ana o, Olorun eledumare yio jeki aje fi ile wa se ibugbe loni o ase. Odu ifa IROSUN OSE/ALAJE lo gate laaro yi, ifa yi fore aje lopolopo fun akapo ti o ba...
View ArticleKílódé tí àwon omoge fi n’ìfé àwon tí ó ti n’íyàwó.
E jòwó mo fé kí e dá mi lóhùn dáadáa. Gbogbo àwon Òré mi tí ó ti n’íyàwó n’ílé ni òpò obìnrin ń súré tè lé, tí ó sì jé wípé àwon àpón bí ti àwa yí obìnrin díè ni ó súré tèle wa, mo ti è fé mò gan. Àti...
View ArticleÌyàwó mi dára sùgbón kò n’ìfé ìbálòpò léyìn ìgbeyàwó.
Ìyàwó mi dáa tí mo sì le pè ní aya rere sùgbón kìí gbà kí á bá ara wa lò nígbà tí ó ye, lóòtó aní omo okùnrin pèlú obìnrin. E jò ó kí ni mo le se? Mo ti gbìyànjú àwon nkan tí mò ti kà ní orí èro...
View ArticleA kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* 🇳🇬 lónìí ooo.
A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* lónìí ooo. Èmí wa yóò se púpò rè láyé. E jòwó, e má sì gbàgbé láti se *ìwúre* fún orílè èdè *Nàìjíríà* nítorí wí pé *”Ìròrùn igi ni ìròrùn eye”*....
View ArticleÀwòrán ìsìnkú Odudu Davis, olóòpá tí ìbon àwon olóòpá ojú omi bà tí ó sì kú...
Ní’sàlé ni àwòrán ìsìnkú olóyè nínú ológun (Corporal) Odudu Davis tí ìbon pa nígbà tí osù kàrún di ogbòn ní inú odún yìí (30/5/2017)láti owó àwon olóòpá ojú omi (naval officer) nígbà tí àwon olóòpá...
View ArticleÀwon apàse ilé-ìwé Obafemi Awolowo University (OAU) pàse kí won mú àwon...
Ogbà Obafemi Awolowo University (OAU) ti kó sí inú dàrúdàpò nígbà tí òpò akékòó tò lo sí àgó olóòpá tí ó wà ní Moore ní ìlú ile-ife láti bèèrè fún ìdásílè àwon akegbé won tí àwon ìgbìmò ìdábòbò Ogbà...
View ArticleÒdómokùnrin odún mókàndílógún (19 years) fé odómobìnrin odún méèdógún (15...
Àwòrán tí ó gba aféfé ni ti àwon tokotayà yí tí oko jé odún mókàndílógún tí ìyàwó sì jé odún méèdógún ní ilè àríwá orílè èdè Nàìjíríà. Ò n lò èro ayélujàra kan ni ó pín àwòrán tokotayà yí, tí ó sì kí...
View ArticleOdó kàyééfi ńlá tí ó wà ní *ADO AWAYE*.
Ìlú kéréje kan wà ní ìpínlè Oyo tí orúko ìlú náà sì ń jé *ADO AWAYE*, òdó kàyééfi kan wà ní ìlú yí tí ó jé wípé bí ènìyàn bá ti esè kan bo inú rè yóò fa eni náà tí a kò sì ní mo ibi tí eni náà ma jásí....
View ArticleOgún-l’ógbòn àwon baba ńlá ìran yorùba l’ójé alágbára, lára won ni *Timi...
Timi Àgbàlé, olóde tí ó sì jé jagunjagun tí Aláàfin rán lo sí ìlú Ede láti dáàbò bo àwon ènìyàn ibè. Alágbára ènìyàn ni Timi jé , tí a sì mò ó sí *Timi Àgbàlé olófà-iná*,gégé bí ìtàn se so, ó jé...
View ArticleEjò tí mo pa nínú ilé Adìe mi lóòní.
Ní òní mo gbèrò láti tún ilé àti àyíká Adìe mi se, ni mo pàdé afayàfà yí, mo sá eré bí mo se le sa mo. Nítorí ìgbà àkókò mi rè é tí mà rí ejò ńlá báyìí láàyè, tí kìí bá se lopélopé omokùnrin kan tí mo...
View ArticleNígbà tí adékódère bá padà s’ábúlé .
Òpò omoge òde-ìwòyé ni a bí sí abúlé sùgbón bí won bá ti jáde díè ìwà àti ìsesí won yóò y’àtò, won á sì gbàgbé orísun won. Èrín pa mí…
View ArticleOmokùnrin Wizkid , Ayo kékeré òun àti ìyá rè múra jáde nínú aso orílé èdè...
Binta Diallo àti omokùrin rè ,king Ayo kékeré jáde lo láìpé tí won sì tàn gan nínú Dashiki won àti aso orílè èdè Nàíjíríà. Aso orílè èdè Nàíjíríà yí jé kí ó dà bi omo Yorùbá tí ó gba okàn obìnrin...
View ArticleOmoge kan ni owó tè tí won sì fi se èsín látárí wípé ó fo odi ilé onílé láti...
Ònlò èro ayélujárá ( Facebook) tí a mò sí Arc Pashal Chike Umeobi ló so wípé arábìnrin yí ni owó àwon figilanté tè ní Ezinifite , ìlú kan ní ìpínlè Anambra . Arábìnrin yí ni won fi èsùn kàn wípé...
View ArticleÀwòrán ìgbéyàwó ògbóntarigì olórin afòròdárà tí orúko rè n jé Gucci mane .
Àfòròdárà (Rapper) Gucci Mane àti Keyshia Ka’oir se ìgbéyàwó alárinrin tí ó jé wípé ogún-l’ógbòn àwon ènìyàn ni won wò ó n’ílé l’óko lórí èro amóhùnmáwòrán.igbéyàwó náà rinlè gan tí ó fi jé wípé...
View ArticleNneoma Nkechi àti Rochas Okorocha pín àwòrán won tí ó ti pé .
E wo àwòrán tipétipé Gómìnà Rochas Okorocha àti ìyàwó rè tí ó rewà, Nneoma Nkechi Rochas Okorocha. Àgbà wá búra bí èwe ò bá se ó rí…
View Article