Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 1429

Omoge kan ni owó tè tí won sì fi se èsín látárí wípé ó fo odi ilé onílé láti jí bisikitì .

$
0
0

       Ònlò èro ayélujárá ( Facebook) tí a mò sí Arc Pashal Chike Umeobi ló so wípé arábìnrin yí ni owó àwon figilanté tè ní Ezinifite , ìlú kan ní ìpínlè Anambra .

Arábìnrin yí ni won fi èsùn kàn wípé ó fo odi ilé láti jí ìpápánu tí a mò sí bisikitì ni owó pálábá rè bá ségi nígbà tí ìkan lára àwon figilanté ri wípé ògbòn n rùn, figilanté náà bá gbìyànjú àti mu sùgbón tí ó bó, ó sì yìn ìbon lùú tí ó sì yè é n ló bá tún fo odi ilé míràn láti balè nínú ilé onílé míràn ,kíá ni onílé yára figbe bonu, béè ni owó bá tè é….


Viewing all articles
Browse latest Browse all 1429

Trending Articles