Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live

Gáàsì bú gbàmù ní Cross river tí ó sì pa èèyàn méji, tí ó fa ìpalára fún àwon...

Àwon omo ebí mérin ti igbákejì adarí kíko eré ìdárayá ní orílè èdè Nàìjíríà ” Vice President of Sport Association (SWAN), Eddie Bekom tí a gbà sí ilé-ìwòsàn léyìn ìgbà tí gáàsì tí wón fi ń dáná bú...

View Article


Àsírí sèsè tú sí won lówó wípé ilé-isé mi ní iye owó tí ó tó Dólà lónà...

Kokomaster tí a tún mò sí D’banj le sèsè di òsèré tí ó lówó jù ní ilè adúláwò (Africa). Olórin tí ó sì jé baba omo kan sèsè gbe sí orí èro ayélujàra (instagram) rè pé Cream platform tí ó jé ilé-isé rè...

View Article


Àwon òrìsà tí e kò mò (sùgbón tí ó ye kí á mò) {Some Orisa you probably don’t...

   Òrìsà Bayani.  Òrìsà alágbára yí ni òrìsà omodé tí a bí pèlú dàda . Ó dára kí a ma bo òrìsà yí kí á sì ma bèèrè fún ìdábòbò, kí á b’orí òtá àti gbogbo ire ilé ayé. Gbogbo ènìyàn ni ó le bo òrìsà...

View Article

Ta Ni Elújoba?

Elújoba ni gíwa tí ó kúrò Lóríi oyè gégé bíi alásé oau Láìpé yìí Tí gbogbo ènìyàn sì n kan sárá sí òjògbòn náà kìí kúkú se pé wón n déédé kan sáárá sí Baba Ìwà rere àti òótó inú tí Baba fi n sisé ló jé...

View Article

Ìbon pa àwon adigunjalè méta tí ìbon bá láti owó àwon òsìsé ìdábòbò (Task...

Òdómokùnrin méta kan ni owó àwon civilian Joint Task Force Nígbà tí won jalè lówó ní Jato Aka ní ìpínlè Benue tí won pa wón ní bíi agogo méjì òwúrò òní (2am). Gégé bí ìròyìn se so, àwon olè náà, ìkan...

View Article


Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigerian jollof rice) ti gbé igbáorókè níbi ìdíje...

Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigeria jollof rice) ti kéde gégé bi ipò àkókó nínú ìdíje àjòdún Washington DC jollof. Ní ojó kejì osù keje odún 2017(july 2, 2017) omidan Atinuke Ogunsalu ti Queensway...

View Article

Ònà tí èèyàn le gbà gbé pèlú onítìjú obìnrin. (Ways To Deal With An...

Tí ènìyàn bá wà lábé òrùlé kan náà, ó ye kí won kókó gbà pé ìwà wa kò le b’ára wa mu. Nígbà kan náà o kò ní láti yí enìkejì padà kí o sì jé oníyè ara re. Kódà bí o bá gbìyànjú tí a kò rí irú rè rí, o...

View Article

Ìbon ba àwon ajínigbé nígbà tí won ń dúnà pàsípààrò lówó ní ìjoba ìpínlè Abia. 

Àwon ajínigbé mérin, èyí tí won ti ń da ìpínlè Abia àti agbègbè rè láàmú. Won ti ń gbìyànjú àti parun tí àwon òtelèmúyé so mó Omoba Division ní ojó ketàdínlógún osù keje (19th July ,2017) ní Ovungwu,...

View Article


Èsì ìdánwò alásekágbá ilé-èkó girama (waec)tí ó burúkú jù nínú odún 2017, tí...

Láàrin ogún-l’ógbòn àwon akékòó tí ó tó 1,559,162 tí won jòkó fún ìdánwò àsekágbá ilé -èkó girama tí a mò sí waec ní odún 2017 tí ó jé wípé òpò ni a ti rí, tí ó sì dára … Akékòó tí ó tó 926,486 ni won...

View Article


Akékòó ilé -èkó Nwafor Orizu College Nsugbe ni àwon omo egbé òkùnkùn yin ìbon...

  Léyìn àrídájú tó ji-n-gí-ri, mo le f’owó s’òyà pé pé ilé-èkó Nwafor Orizu College of Education Nsugbe ti pàdánù tí ó pò .   Arákùnrin Mr Osaji Charles, tí ó jé Mr NASELS télè (2013/2014 session), ni...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

John Nani Pa Olúfà Ńlá, John Nani Tí Ó Jé Konmísónà Ní Ìpínlè Delta. 

 Konmísónà tí ó ń mójú tó àyíká (commissioner of environment), tí a mò sí Hon. Barr John Nani àti àwon emèwà rè kolu tí won sì pa olúfà ńlá tí ó won òsùwòn tí ó tó mítà lónà mérin ó dín mérin (3.6m) ní...

View Article

Wón pa ológun Nàìjíríà kan ní Sambisa lónìí.

Gégé bí olùrànlówó oníròyìn ti ìjoba ìpínlè Sokoto, Imam Imam òsìsé ológun (army officer) M Maiwada àwòrán eni tí ó wà lókè tí ó sèsè di Balogun (captain) ni won yín ìbon pa ní ojú ogun pèlú àwon Boko...

View Article

Àwon agbésùmòmí Boko Haram pa àwon àgbè àti àwon ará ìlú ní Borno.

Ókéré jù àwon ènìyàn méèdógún (15) ni a gbó pé àwon agbésùmòmí Boko Haram pa nígbà tí won kolu ara won. Ìròyìn tí Orísun àwon figilanté gbé ni wípé òpò àwon ará ìlú ní won sì ń wá léyìn Ìsèlè tí ó...

View Article


Ohun méje tí ó jé èdùn okàn tí won kò so fún mi kí n tó parí ilé-èkó gíga...

Ohun méje (7) tí ó jé èdùn okàn tí enikéni kò so fún mi kí n tó parí ilé-èkó gíga. 1- ilé-èkó gíga ifáfitì wà fún mímo irú èèyàn tí o jé, lo àkókò àti ànfààní tí o bá ní dáadáa, láti mo ìlépa re tí ó...

View Article

Kinin Oruko Ara Kunrin Yi ?????

(gbajugbaja osere oni theatre )

View Article


Yoruba dun kaa

Ti o ko ogorun ebe. Ti o wa de ile ti n so fun gbogbo eniyan wipe Igba ebe loun ko loko … Eyin efi IRU eniyan be sile. Nigba ti o BA je ogorun otito tan. Funrare na Ni yio tun da je ogorun iro…

View Article

Àwon òjògbón lòdì sí ìbára eni lòpò láì lo ìdábòbò.

Dókítà tí ó ń wo àìsàn tí ó je mó èyà ara omo bíbí (Gynecologist) Dr. Uche Ene, ti gba àwon òdó ní ìmòràn kí won yàgò fún ìbálòpò tí kò ní ìdábòbò kí won má ba kó Àtòsí (gonorrhea) láti ní ìlera tó...

View Article


Àwon ènìyàn Nàìjíríà ní orí èro ayára-bí-àsá so pé kí won fún Cynthia...

Àwon ènìyàn Nàìjíríà ní orí èro ayára-bí-àsá so pé kí won fún Cynthia Chinecherem ní egbèrún lónà lónà aárùndínlógbòn lé ní èédégbèta náírà (#525k) fún níní àmì “A” mésàn-án (9A1) nínú èsì ìdánwò...

View Article

Olùkó kan ní Benue ni won ní kí ó San mílíònù kan àti ààbò Náírà (₦1.5m) fún...

Arákùnrin tí ó sèsè parí èkó, tí ó sì ń sisé olùkó ní ilé-ìwé aládàáni girama kan tí ó fé fé ìyàwó ní àwùjo kan ní Zone “A” ní ilè Tiv ní ìpínlè Benue, ni won ti fún ní àwon ohun tí yóò rà tí àpapò rè...

View Article

Eré odún Òrìshà ní orílè èdè UK Edinburgh Fringe.

Àwon Òrìshà, Yemoja, Oya, Òshun, Elégba àti òshóòsì jé àwon Òrìshà tí ó dúró fún èdá ènìyàn ní gbogbo ònà, tí won sì máa ń wá sí ayé gbangba. Nígbà tí akoni wa òshóòsì, tí ó jé ògbójú ode, tí ó sì jé...

View Article
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live