Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live

Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia, Okezie Ikpeazu ti fara kásá àrùn Covid-19

Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia, Okezie Ikpeazu ti fara kásá àrùn Covid-19 Bí àwọn èèyàn kan ṣe rò pé eré orí ìtàgé ni ariwo t’íjọba ń pa lórí àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí Kòrónáfairọ̀ọ̀sì yìí, bẹ́ẹ̀ ni Ìjọba...

View Article


Ìdájọ́ ikú kò pọ̀jù fún gbogbo afipá bánilòpọ̀ – Ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn

Ìdájọ́ ikú kò pọ̀jù fún gbogbo afipá bánilòpọ̀ – Ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn Àgbáríjọpọ̀ àwọn ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọmọnìyàn bíi mẹ́rìnlà ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ti korò ojú sí ìwà ìfipábánilòpọ̀ àti ìṣekúpani tí àwọn...

View Article


O̩wó̩ pálábá 185 nínú o̩mo̩ e̩gbé̩ òkùnkùn ségí l’Eko

O̩wó̩ pálábá 185 nínú o̩mo̩ e̩gbé̩ òkùnkùn ségí l’EkoYínká Àlàbí Komisona olopaa ni ipinle Eko, Ogbeni Hakeem Odumosu tenu moo ipinle Eko ko ni faaye gba egbe okunkun rara. Eyi lo faa to fi tete...

View Article

Ìjo̩ba àpapò̩ kéde ‘June 12’ gé̩gé̩ bí o̩jó̩ ìsinmi lé̩nu isé̩

Ìjo̩ba àpapò̩ kéde ‘June 12’ gé̩gé̩ bí o̩jó̩ ìsinmi lé̩nu isé̩ Lati odun to koja ni ijoba apapo ti yi ojo isejoba awa-ara-wa kuro ni ojo kokandinlogbon osu karun-un odun si ojo kejila osu kefa odun....

View Article

Olu Jacobs sì wà láàyè

Olu Jacobs sì wà láàyè Agba oje ninu ere ori itage ni ede Oyinbo, Alagba Olu Jacobs ni awon iroyin eleje kan n gbee kiri lori ero ayelujara lati aaro oni pe, “olodi baba naa ti lo je ipe awon baba nla...

View Article


Èèyàn 627 ló lùgbàdì àrùn Coronavirus ní Naijiria ní Ọjọ́ Ẹtì

Èèyàn 627 ló lùgbàdì àrùn Coronavirus ní Naijiria ní Ọjọ́ Ẹtì Ẹgbẹ̀ta lé lọ́gbọ̀n o dín mẹta èèyàn (627 )tuntun míì ló ṣẹ̀sẹ̀ lùgbàdi àrùn Kofi -19 ní Nàìjíríà. Àjọ tó ń rí sí ìdènà àti amójútó...

View Article

Orisirisi: Àwọn àǹjàǹnú ń gbowó oṣù l’ájọ Sùbẹ́ẹ̀bù Kwara- EFCC

Àwọn àǹjàǹnú ń gbowó oṣù l’ájọ Sùbẹ́ẹ̀bù Kwara- EFCC Àjọ tó ń gbógun ti ìwà jẹgúdújẹrá lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà EFCC sọ pé àṣírí àwọn ayédèrú òṣìṣẹ́ ẹgbẹ̀rún kan àjọ tó ń ṣàkóso ètò ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀...

View Article

Bàbá mi máa jáwé olúborí ipò Ààre̩ ló̩dún 2023 – Adamu Atiku

Bàbá mi máa jáwé olúborí ipò Ààre̩ ló̩dún 2023 – Adamu Atiku Alhaji Atiku Abubakar ni igbakeji Aare tele ri ni orileede yii. Oun ni igbakeji Oloye Olusegun Obasanjo nigba naa.Atiku dije du ipo Aare ni...

View Article


Èmi ò ní fàá ká jáa pè̩lú Tinubu – Aregbesola

Èmi ò ní fàá ká jáa pè̩lú Tinubu – Aregbesola Gomina tele ri ni ipinle Osun, Ogbeni Rauf Aregbesola ni o tinsalaye ni aimoye igba pe oun ko ni Ojogbon kankan pelu Asiwaju Bola Tinubu.O ni “ogede ko le...

View Article


O̩jó̩ ìdìbò kò sún síwájú ní Edo – INEC

O̩jó̩ ìdìbò kò sún síwájú ní Edo – INEC Alaga patapata fun eto idibo ni orileede yii, Ojogbon Mahmood Yakubu lo n salaye yii ni ilu Abuja.O ni pelu rogbodiyan to n lo ni ipinle Edo, awon kan ti n gbee...

View Article

L’ẹ́gbẹ́ òṣèlú APC; alága méjì lójijì lalẹ̀ hù—- Ajimobi àti Victor Giadom

L’ẹ́gbẹ́ òṣèlú APC; alága méjì lójijì lalẹ̀ hù—- Ajimobi àti Victor Giadom Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní bí ọ̀rọ̀ ńlá kò bá tí ì tán, èèyàn ńlá kò níí sinmi àròyé.Sinimọ́ oríta sì ń tẹ̀síwájú pẹ̀lú ọ̀rọ̀ tó...

View Article

Ilé ẹjọ́ kòtẹ́mílọ́rùn yọ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC Adams Oshiomhole nípò

Ilé ẹjọ́ kòtẹ́mílọ́rùn yọ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC Adams Oshiomhole nípò– Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ti ilú Àbújá ti yẹ àga mọ́ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC, Adams Oshiomhole nídìí Ìgbìmọ̀ ẹlẹ́ni mẹ́tà ti adájọ́...

View Article

Fidio: Ipinle Eko

The post Fidio: Ipinle Eko appeared first on Ọmọ Oòduà.

View Article


Eṣọ́ àjọ FRSC mẹ́ta tí ààrá sán pa gbọdọ̀ ṣ’ètùtù – Ẹlẹ́buùbọn

Eṣọ́ àjọ FRSC mẹ́ta tí ààrá sán pa gbọdọ̀ ṣ’ètùtù – Ẹlẹ́buùbọn Ṣé ọlọ́tọ̀ ní t’óun ọ̀tọ̀, a díá fún òkú tó kú ńlé, tí wọ́n sin s’óko.Àgbà Imọlẹ̀ kan nlẹ yìí ti fèsì sí ìṣẹ̀lẹ̀ ààrá tó sán láìpẹ́ yìí...

View Article

Kíní orúkọ tí wọn npè Ìsọ yìí ní èdè ìlú ti’yin?

Aku ataro óò Adé kú ọjọ yìí Kíní orúkọ tí wọn npè Ìsọ yìí ní èdè ìlú ti’yin náà?????? #iya lájé The post Kíní orúkọ tí wọn npè Ìsọ yìí ní èdè ìlú ti’yin? appeared first on Ọmọ Oòduà.

View Article


Igbákejì gómìnà Òǹdó Agboola Ajayi tilé APC bọ́sí yẹ̀wù PDP

Igbákejì gómìnà Òǹdó Agboola Ajayi tilé APC bọ́sí yẹ̀wù PDP Ó dà bíi pé , ẹ kú àtilé bọ́ọ́lé ló kù báyìí, tí àwa òlùdìbò yóó ma kí àwọn olóṣèlú wọ̀nyí lásìkò yìí, tí wọ́n kàn ń múwa ṣeré nínú ọpọlọ,...

View Article

INEC kọ lẹ́tà APC láti ṣe ìbò abẹ́nú l‘Ondo

INEC kọ lẹ́tà APC láti ṣe ìbò abẹ́nú l‘Ondo Ṣé àwọn àgbà ní bí eégún kò bá ṣe n tó tóbi, atọ́kùn rẹ̀ kìí tú ìdí rẹ̀ wò. Àjọ olómìnira tó ń ṣe kòkárí ètò ìdíbò Orílẹ̀ yìí tí fọnmú báyìí pẹ̀lú gbólóhùn...

View Article


Abọ ìwádìí yóó ṣọ pàtó ikú tó pàwọn òṣìṣẹ́ wa– Àjọ FRSC

Abọ ìwádìí yóó ṣọ pàtó ikú tó pàwọn òṣìṣẹ́ wa– Àjọ FRSC Ìlú u gángan lọ̀pọ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ láyé,n Iàwọn àgbà se ṣọ pé,ẹ̀yìn ló kọ sẹ́nìkan, n tó kọjú sẹ́lòmíìn.Bí a kò bá gbàgbé, àìpẹ́ yìí ni ìṣẹ̀lẹ̀...

View Article

Abiola Ajimobi sùn un re

Ikú pàgbẹ̀ àṣírí aláró tú.Ikú pàlùkò àbùkù kará ìkosùn.Ọrùn má kánjú, gbogbo wa la dágbádá ikú.Ìgbà átàsìkò ẹ̀dá ló só kùnkùn.Gíńgín ladáhunṣe tó mewé e re.Gbogbo wa lòpè nípa àkúnlẹ̀yàn.Òkú ń sunkú...

View Article

Ògún Majek wọ káà ilẹ̀ sùn

Ògún Majek wọ káà ilẹ̀ sùn Ọlọ́jọ́ ń kajọ́, ẹ̀dá ò fiyè si.Ìjọ ọmọ tuntun dáyé, nijọ́ ìdùnnú, ẹ̀rín, òhun ọ̀yàyà fún ẹbí,ará, pẹ̀lú ìyekan. Ṣùgbọ́n kìí rọgbọ ká sàdédé sàfẹ̀kù èèyàn ẹni pékú yọwọ́ ọ...

View Article
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live