Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live

Ènìyàn 148 míràn lárùn Covid-19 ní Nàìjíríà–Àjọ NCDC

Ènìyàn 148 míràn lárùn Covid-19 ní Nàìjíríà–Àjọ NCDC Ó ti pé ẹgbẹ̀rún mẹ́ta àti márùndínládọ́jọ èèyan tó ti ní àrùn apinni léèmí yìí ní Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ Èkó ló ṣì ń léwájú.Ní bí a ṣe ń kó ìròyìn yìí...

View Article


Kofi 19 dẹ́yẹ sí ìpínlẹ̀ Kogi àti Cross River –Osagie

Kofi 19 dẹ́yẹ sí ìpínlẹ̀ Kogi àti Cross River –Osagie Àwámárídìí ni iṣẹ́ Elédùwà, ṣùgbọ́n ọmọ èèyàn lọ́pọ̀ ìgbà má a ń fẹ́ tú fín ìn ìdí i kóòkò láti mọ kín gán án ní ń gbénú-un rédíò fọhùn. Bí kò bá...

View Article


Èeyàn 239 míràn ni àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Èeyàn 239 míràn ni àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà À fi kí Ọlọ́run sàánú wa lórí àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí kòrónáfairọ̀ọ̀sì yìí tó ń gbomi lójú t’olórí t’ẹlẹ́mù, bí Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí...

View Article

Ewì Toni: Ìwà rere

*Ìwà rere*Iléere ní ẹ̀ṣọ́ nínúÌwà’bàjé ní jẹ́ k’ọ́mọ o j’ìyàẸwúrẹ́ ya aláìgborànÀgùntàn jẹ́ oníwàpẹ̀lẹ́Adígbánnákú ṣẹ̀yìn gákangàkan Iléere ní ẹ̀ṣọ́ nínúÌwà rere lẹ̀sọ́ ènìyànÌwà rere ni òbí ní,tí...

View Article

Ó dìgbà Kehinde Ayoola, Makinde, PDP, APC, ALGON ,ṣe ìdárò akọni

Ó dìgbà Kehinde Ayoola, Makinde, PDP, APC, ALGON ,ṣe ìdárò akọni Bá a kú làá dère, èèyàn kò sunwọ̀n láàyè.Gómìnà Ṣèyí Mákindé ti sàpèjúwe ọ̀kan lára àwọn Kọmíṣọ́nnà rẹ̀, Kẹhinde Ayọọla tó papòdà ní...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìjọba àpapọ̀: À nì sẹ́, dan dan l’óúnjẹ ọfẹ fún ọmọ rẹ, kíláàsì kínní dé...

À nì sẹ́, dan dan l’óúnjẹ ọfẹ fún ọmọ rẹ ,kíláàsì kínní dé ìkẹta alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀- Ìjọba àpapọ̀ Iléeṣẹ́ tó wà fún ìpèsè ohun ìrànwọ́ nílẹ̀ wa ló sísọ lójú ọ̀rọ̀ yìí nínú àtẹjáde kan tó fisíta lójú òpó...

View Article

Raymond Dokpesi sé̩gun àrùn covid-19

Raymond Dokpesi sé̩gun àrùn coronae̩i Aja to rele Ekun to bo, o ye ki a kii ku ewu.Gbajugbaju oludasile ileese redio ati telifison Ray power ati AIT ni o se alabapade ajakale arun coronavirus ni nnkan...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ti ṣe àfihàn àwọn afurasí tó jí ìbejì Akeugbagold gbé ní ìlú...

Iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ti ṣe àfihàn àwọn afurasí tó jí ìbejì Akeugbagold gbé ní ìlú Ìbàdàn Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní, àṣẹgbé kan kò sí, àsepamọ́ ló wà.Ni báyìí, kélé òfin ti mú àwọn ọ̀daràn tó jí àwọn ìbejì...

View Article


Èèyàn ẹgbẹ̀rún kan àti irínwó dín mẹ́fà bá Kofi 19 rìn l’Amẹ́ríkà lópin ọ̀sẹ̀.

Èèyàn ẹgbẹ̀rún kan àti irínwó dín mẹ́fà bá Kofi 19 rìn l’Amẹ́ríkà lópin ọ̀sẹ̀. À fi kí á bẹ Ọlọ́run kó báwa dáwọ́ ibi dúró nílẹ̀ yìí àti lókèèrè to rí igbi gbogbo la lẹ́ni sí lórílẹ̀.Gbogbo ìgbà ni...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ọmọọsẹ́ tó súnmọ́ mi jù lọ satọ́nà bí wọ́n se jí ìbejì mi gbé — Akewugbagold

Ọmọọsẹ́ tó súnmọ́ mi jù lọ satọ́nà bí wọ́n se jí ìbejì mi gbé — Akewugbagold Ṣé wọ́n ní olè kò ní jàgbà, kó má kó fìrí, bẹ́ẹ̀ bíkú ilé ò pani,yóó sòro díẹ̀ kí kú tòde pààyàn . Ọ̀rọ̀ kò rí bẹ́ẹ̀ ni...

View Article

Ọ̀daràn kan fi tipá wọ ààfin Ọ̀ọni ilé ifẹ̀

Ọ̀daràn kan fi tipá wọ ààfin Ọ̀ọni ilé ifẹ̀ A kìí gbélé ẹni ká fi ọrùn rọ́ ni a ti ń gbọ́ tipẹ́ tipẹ́, sùgbọ́n kín wá ni ká ti pe tirúfẹ́ ìṣẹ̀lẹ̀ ajániláyà yìí tó wáyé ní ààfin Ọọ̀nirìṣà Ọba Adéyẹyè...

View Article

Ààrẹ Buhari dijú lé Ọ̀gá Àjọ NECO àti àwọn mẹ́rin mìíràn tó jàjẹbánu

Ààrẹ Buhari dijú lé Ọ̀gá Àjọ NECO àti àwọn mẹ́rin mìíràn tó jàjẹbánu Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari ti fi ọwọ́ òṣì júwe ilé fún adarí àjọ elétò ìdánwò àṣekágbá ti girama, NECO àti àwọn...

View Article

Èsì àyẹ̀wò tuntun Nàìjíríà fihàn pé “313” èèyàn ti gbàlejò Kofi 19 …àjọ NCDC

Èsì àyẹ̀wò tuntun Nàìjíríà fihàn pé “313” èèyàn ti gbàlejò Kofi 19 …àjọ NCDC À fi kí á bẹ Ọlọ́run kó bá wa dásí ọ̀rọ̀ àjàkálẹ̀ àrùn ajániláyà pàtì yìí, bí àwọn tó ní kòrónáfairọ̀ọ̀sì ní Nàìjíríà ti ń...

View Article


Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ máa wo̩lé láìpé̩

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ máa wo̩lé láìpé̩ Gbogbo igbiyanju ni awon ajo eto eko ti wa ninu awon ajo NCDC n se bayii lati le je ki awon akekoo wole eko won. Oro arun coronavirus yii ti su gbogbo aye. Ile ti su...

View Article

Àjo̩ NCDC mú mé̩ta nínú oògùn ìbíle̩ fún ìwòsàn covid-19

Àjo̩ NCDC mú mé̩ta nínú oògùn ìbíle̩ fún ìwòsàn covid-19Yínká Àlàbí Ajakale arun ti gbogbo eniyan ro pe ko ni pe fi orileede yii sile, lo ti ko ti ko lo mo yii. Eyi lo wa bere si ni ko gbogbo aye...

View Article


Ìṣẹ parí fún òṣìṣẹ́ tó bá gbé àṣírí Ìjọba jáde lọ́nà àìtọ́—Ìjọba àpapọ̀

Ìṣẹ parí fún òṣìṣẹ́ tó bá gbé àṣírí Ìjọba jáde lọ́nà àìtọ́—Ìjọba àpapọ̀ Ṣé àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní, ìlú tí kò sófin, ẹ̀sẹ̀ kò sí níbẹ̀, gẹ́lẹ́ bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ Orílẹ̀ yìí dà báyìí, bí Ìjọba àpapọ̀ se ni...

View Article

Covid-19 ló sàkóbá fún isé̩ e̩gbè̩rùn kan, ìjo̩ba ìbíle̩ kan – Festus Keyamu

Covid-19 ló sàkóbá fún isé̩ e̩gbè̩rùn kan, ìjo̩ba ìbíle̩ kan – Festus KeyamuYínká Àlàbí Agbejoro agba to n ja fun eto omoniyan to tun je minisita eto ise fun ipinle, Festus Keyamu lo n salaye fun awon...

View Article


O̩ló̩run sì máa gbè̩san ikú bàbá mi – O̩mo̩ o̩ko̩ olóyún

Olorun si maa gbesan iku baba mi – Omo ojo OloyunOjo ketalelogun osu kin-in-ni odun yii ni awon adiha-Moran kan lo yinbon pa Alhaji Fatai Yusuf ti gbogbo eniyan mo si oko oloyun. Lati igba naa ni awon...

View Article

Auxiliary, ata dùǹdú rẹ̀ ń fínmú — Ìjọba Ọ̀yọ́ dúnkookò

Auxiliary, ata dùǹdú rẹ̀ ń fínmú — Ìjọba Ọ̀yọ́ dúnkookò Ó dà bí ẹni pé orí tí yóó súpó, kìí jẹ́ kí ti ọlọ́kùnrùn ó yè ni ọ̀rọ̀ fẹ́ dà báyìí fún asáájú ìgbìmọ̀ tó ń ṣe àkóso gárèjì ọkọ̀ ní ìpínlẹ̀...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

KṒJṒDÁ 10062: Odún Dé Omo Eríwo…

Happy world Ifa Festival to all the traditionalist around the globe.Irinwó imolè, igba imolè, Olódùmarè yóò gba gbogbo irè wa, àmódùn á jù báyìí lo. We shall all witness more of it on earth. Ajoke...

View Article
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live