Iyawo tagbe wani ojo aiku mati soro, egbo bose wi
Olotu: ekasan ooo eyin ara ile,asiku asiko yin, eledua yowa pelu gbogbo wa o,ase. Iyawo tagbe wani ojo aiku mati soro egbo bose wic….Gbogbo eyin ebi mofe ki e fi ise yin bura fun mi pe ti moba so e ni...
View ArticleOre yeye Osun!
May we all be blessed today and beyond. Ore yeye Osun! Take it to the river. Ore yeye Osun! – – –
View ArticleIwure owuro 26.07.2016
*Aje ko ni di ota a mi. *Edumare dakun fidi aje sole nile mi. *Imo ota, imo elenini ko ni se lori mi. *Emi ko ni di eni arisa ati arisunkun. *Edumare fi aso iyi wo mi(Ase). Aare Olasunkanmi Alani...
View ArticleOdu ifa IROSUN OPINNI/ IROSUN ORO
| | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, gegebi oni se je ojo isegun olorun alagbara yio muwa bori Ogun ota ase. Odu ifa IROSUN OPINNI/ IROSUN ORO lo gate laaro yi, ifa...
View ArticleIre ni mo ko
Ire ni mo ji ri Ire tororo d’ori awa o Ire toorun ogberi o mo o Aase IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole
View ArticleOlojo Ibi Ti Oni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa Omolola Adex ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba Atata. Maami Olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia ara ati ibale...
View ArticleOgbon O Di Igi A Fi Okun(Rope) …
Ojulu, ti opo-eniyan bama wi won a ni ogbon o di igi a fi okun(rope) won a tun ni kosi abuja(short-cut) lorun ope, sugbon ogbon di igi fun eni ti eledua ba gbon, be sini abuja ‘be lorun ope ti olohun...
View ArticleOunje Emi Fun T’ooro Yii – 29.07.2016
HUN !!! Otito wa da bi Akisa Elegbin ni niwaju Oluwa … WOO ORE WA !! Bawo lo se roo pe o mo (mi) to… Nje iwo ri ara re gege bi Ododo loju gbogbo aye ? Se iwa re lo dara julo ti o n ri...
View ArticleOdu Ifa Irosun Afin/ofun
| | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin tu ku isimi opin ose, eledumare yio rojo ibunkun sinu aye wa loni o ase. Odu ifa IROSUN AFIN/OFUN lo gate laaro yi, ifa...
View Article“B’éni l’ówó bí ò n’íwà, owó olówó ni
B’éni l’áya bí ò n’íwà, aya aláya ni B’éni bí’mo bí ò n’íwà, omo olómo ni If one has money but lack character, it’s someone else money If one has wife but lack character, it’s someone else wife If one...
View ArticleOdu Ifa Irosun Ika/Oromosunka
| | | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana, a sin ku isimi oni emin wa yio se pupo re laye ninu alaafia ara o ase. Odu ifa IROSUN IKA/OROMOSUNKA lo gate laaro yi, ifa yi...
View ArticleA o ni jin sofin aye pelu ase Olodumare. Ase o…
Ofun saa lefun Ofun saa losun Ofun saa ni moriwo Ope yeyeye A difa fun Alagemo terekange Tii se Omo Orisa igbowuji Nitori ajeku Baba Alagemo Nitori amunku Baba Alagemo Won ni ki Alagemo losi apookun...
View ArticleIwure Osu Tuntun 01/08/2016
E MAA WI TELE MI : Ire ayo ni temi losu yii. Ire idunnu ni temi losu yii. Ire owo ni temi losu yii. Edumare foro mi se’yanu lose yii. Igbega ati aseyori ni temi. Osu yii yoo san mi si rere. Akoba,...
View ArticleOgulutu Oro Toni – 01.08.2016
Hummmmmm were were odunyi tun pari lo re. Humm Oya bi arare lere Wipe lati ibeere odunyi tofi di akoko tawa. Kilo ti gbese????? Hummmmmm Woo orewa Nje o mope Olohun koda o lasan bi? Maduro toraye gan...
View ArticleOwe ati Ibeere Toni – 05.08.2016
– Dabimoseda Alaisan toni ohun o je eyin(egg) ejo(snake) Ibeere Toni -nje IFE otito siwa bi tati jo mo bi?
View ArticleOri Eni Lawure Eni O – Iyalorisa Omitonade Ifawemimo
Ori Eni Lawure Eni O Ori Eni Lawure Eni Mo ji lowuro mo dewo mori O Ori Eni Lawure Eni… Ki Ori wa ma sowa nu ooo… Ase Ire O! Translation One’s Spiritual/Inner head is his/her super spell(2ce) I woke up...
View ArticleOdu Ifa Owonrin Obara – Faniyi David Osagbami
| | | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si ku isimi opin ose, mo gbaladura laaro yi wipe ako ni pejopo sunkun ara wa o ase. Odu ifa OWONRIN OBARA lo gate laaro...
View ArticleOdu Ifa Owonrinsindin/edi
| | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, eledumare yio pin ere kanwa o, ayo ojo oni koni fiwa sile o ase. Odu ifa OWONRINSINDIN/EDI lo gate laaro yi, ifa yi gba akapo...
View ArticleHappy Isese Day (August 20th) in advance!
Iba Olodumare Iba Ifa Olokun Asorodayo Iba Obatala Oseeremagbo Iba gbogbo Irunmole Isese Day yio ba wa layo! Aase! Happy Isese Day (August 20th) in advance!
View ArticleA ku Ose Sango!
Owonrin Odi I II II II II I I I Owonrin sindin sapere Adifafun Bata abufun Sango nijo won torun bowaye ebo won ni kiwon ose awon mejeji gbebo won sisebo Bata ni owonrin sindin sapere Sango ani okuu...
View Article