Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 1429

A ku Ose Sango!

$
0
0

Owonrin Odi
I II
II II
II I
I I

Owonrin sindin sapere Adifafun Bata abufun Sango nijo won torun bowaye ebo won ni kiwon ose awon mejeji gbebo won sisebo Bata ni owonrin sindin sapere Sango ani okuu temi iyi kotan lara awon mejeji aye koni gba iyi ara emin ateyin akuojumo Sango yobawa segun Ota Arabanbi afigba Ota segun kabiyesi Sango ooooooooo

Aare Aderemi Adedosu Ododoifa


Viewing all articles
Browse latest Browse all 1429

Trending Articles