Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 1429

Awakò kan tí kò fi ara balè ní ojú pópó ti fi okò fó orí omokùnrin kan ni ìpínlè Edo.

$
0
0

Òdókùnrin kan ni ó se àgbákò ikú òjijì ní ojó mélòó séyìn ní ìlú Jatu ní ìpínlè Edo, nígbà tí ó n gbìyànjú láti fònà sí òdì kejì, arákùnrin yí ni okò tí o n sáré fó ní orí tí ó sì pa á lésèkesè.
Ìsèlè burúkú yí ni a gbó wípé ó n fa wàhálà ní agbègbè náà kí ó tó di wípé won gbé òkú náà kúrò lónà.


Viewing all articles
Browse latest Browse all 1429

Trending Articles