Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 1429

Reekado banks wà pèlú àwon òdóbìnrin tí won yááyì “ka bíbélì re kí o sì gbàdúrà lójojúmò.

$
0
0

Ìkan lára àwon omo olórin abé ikò Marvin, Reekado banks pín àwòrán sí orí èro ayélujára tí a mò sí instagram, èyí tí ó yà pèlú àwon òdóbìnrin tí won férè wà ní ìhòhò. Tí ó sì ko síbè pé Ka bíbélì re kí o sì gbàdúrà ní ojojúmó.


Viewing all articles
Browse latest Browse all 1429

Trending Articles