Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live

Awon aye tun pade Fayose nile alapata

Gomina ipinle Ekiti, Ayodele Peter Fayose tun gbe ara mii yo pelu bo se gba obe alapata mu niso alapata eran to si bere si ni ge eran fun awon kositoma. The post Awon aye tun pade Fayose nile alapata...

View Article


Egan dogo: Omobirin ti o lese n pa $1000 lojumo

The post Egan dogo: Omobirin ti o lese n pa $1000 lojumo appeared first on Ọmọ Oódua.

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ojulowo-ogidi iya je awon ole ti won mu ni Mowe

Ojo gbobo ni tole, ojo kan pere ni tolohun. Owo palanba awon igara olosa kan segi laaro ana ni agbegbe Olowotedo Mowe to wa ni masose Eko si Ibadan. Ikanra ni awon eniyan agbegbe naa fi na awon ole taa...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

E wo ohun ti Gomina Ambode ko fun awon agbofinro ilu Eko

Gomina Ambode ti ilu eko ti ko opolopo ohun elo bi moto, oko ojuomi, oko ofurufu ati okada fun awon agbofinro ipinle naa lati le gbogun ti iwa idaran ni ipinle naa. Minisita fun eto abenu, Rahman...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Oju oge orekelewa iyawo K1 oba Fuji tasansan

Titi Masha ni yii, okan ninu awon orekelewa obirin ti K1 de Ultimate fi n segbaladun niyewu. Titi rewa pupo lobirin, oju re ri rekete bi ojo, ibadi aran ti n danilorun nigba gbogbo. [Olayemi, ara n fu...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

E wo ohun ti won so nipa Basiru Alaaru niluu Abuja

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Awon Foto Kunle Afolayan niluu Kenya

Die ni yii ninu ibudo ere fiimu tuntun Kunle Afolayan, The CEO, ni ilu Nairobi to wa ni Kenya.

View Article

Omo Gomina Ambode n je igbaladun Sande lowo

Kosi ise lonii ojo Sande l’Alausa. Ile ni Habib Aruna, akowe iroyin fun gomina Akinwunmi Ambode, wa pelu aya re. Awon mejeeji jo n je igbaladun ara won loni miliki.Ki lo tile kan mi na lori oro oko ati...

View Article


Oba’binrin Asa Solaade Iyaasa: Ohun IFA ati Iwure

ÒÒṢÀ ÒKÈ, ÌBÀ IFA ni ti a ba ji a ki OLU OLU moji mo ki o loni IFA ni to a ba ji a ki Osin, osin moji mo ki o loni ELA ni kan ni somo bibi inu Agbomiregun Nigba to n ti ode orun bowa si ode isalaiye,...

View Article


Fayose niso eleja

E tun gbe yewo, Gomina Foyose tun gbe sunmo iya eleja.

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

“Gbajue paraku ni Dokita Akintunde Ayeni” -Onibara Yem-Kem lo so bee

Arabirin Bamidele Ademola-Olateju lo gbe atejade kan sori ero FACEBOOK re nipa alase Yem-Kem International, Dokita Akintunde Ayeni. O ni gbajue paraku ni  maanu naa. Ohun ti arabirin Bamidele tun wa...

View Article

Oga olopaa yari ooo

Kosi ohun teeyan ko ni ri tan ni Naija yii sa. lol

View Article

IROYIN OWURO ose yii ti jade oooooooo

Ese ‘o gbero ni Ikenne Paradise ni mama wa bayi – Pst Adeboye Opelope Mama Kapenta nii nba je – Pst Bakare Okunrin to feran ibalopo pelu okunrin farahan ni Abeokuta Oju to maa ti awon ti won nbu ijoba...

View Article


AṢẸ: Irosun di awo ẹlẹtà ádífá fun ẹlẹtá eyi..

Irosun di awo ẹlẹtà ádífá fun ẹlẹtá eyi tin se owun gbogbo ti ikan ko lori (wọn ni ẹbọ nikose..orùbọ tan lowa di oni re gbogbo) Njẹ ori ẹni ni awure, eníyan bí ẹbáá ji lowurọ kí ẹdí ẹlẹ́da...

View Article

Nje Eyin Ranti Oruko Tonje ?

Edakun, e ba wa dasi oro ton lo   Nje Eyin Ranti Oruko Tonje ?

View Article


Oselu ipinle Oyo: Alao Akala ti wa ogbon mii da

Christopher Alao Akala ti wa ogbon mii da Nibayii ti Christopher Alao-Akala, eni odun marunlelogota (65) ti pinnu lati darapo mo egbe APC lati inu egbe Labour Party ni awon awuyewuye kan ti bere si ni...

View Article

“Oruko awon to ja Naijiria lole ko ni pe jade”– Buhari

Aare Buhari ti fi da awon omo Naijiria loju wi pe, laipe, awon oruko awon ojelu ti won ko owo Naijiria je ko ni pe di tite jade fun gbogbo aye. Gege bi oro re, eleyii to se nibi ipade Anyiam-Osigwe...

View Article


Gobe sele lagbo Davido

Orisiirisii ara ni awon omo olorin igbalode maa n da lagbo ere orin. Iru ara bee ni bi ki won bo aso lorun ki won si ju si aarin ero onworan. Awon mii a maa bo alakorun danu soju agbo lati fi ife han....

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

E kaabo si aafin Ooni Adeyeye Enitan Ogunwusi

E kaabo si aafin Ooni Adeyeye Enitan Ogunwus   The post E kaabo si aafin Ooni Adeyeye Enitan Ogunwusi appeared first on Ọmọ Oódua.

View Article

Ile ejo to gaju lo ni yoo pari idaju iku Reverend King

Ile ejo to gaju nile yii ti kede ojo kerindinlogbon osu keji odun ti n bo (26/02/15) gege bi ojo ti igbejo adari ijo Christian Praying Assembly, Reverend Chukwuemeka Ezeugo, ti gbogbo eniyan mo si...

View Article
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live