E̩ Fi Àdúrà Rànmí Lọ́wọ́, Nítorí Ọmọkùnrin Mi Ti Lùgbàdi Àrùn Coronavirus …...
Ẹ fi àdúrà rànmí lọ́wọ́, nítorí ọmọkùnrin mi ti lùgbàdi àrùn coronavirus … igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀ yìí nígbà kan Fẹ́mi Akínṣọlá Àjàkálẹ̀ àrùn kan tí gbogbo àgbáláayé ń kó bẹ́ẹ́rẹ́ fún lásìkò yìí tí kò...
View ArticleÀfàìmọ̀ Kí Coronavirus Má Dà Bí I Ti China Tabi Italy- Mínísítà Kìlọ̀
Ẹni mẹ́rin mì ìn kó àrùn apinni ní mímí èèmii coronavirus ní Nàìjíríà,àfàmọ̀ kò mọ́ dà bí i ti China,l Italy— Mínísítà kìlọ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Ìgbọrọ̀ sàn ju ẹbọ rúrú fún ẹni tó bá fẹ́ gbọ́ ni o.Ó ti di...
View ArticleRonaldinho Ń Kó̩ Is̩é̩ Gbé̩nàgbe̩nà Nínú È̩wò̩n Ní Orílèèdè Paraguay
Ronaldinho ń kó̩ is̩é̩ gbé̩nàgbe̩nà nínú è̩wò̩n ní orílèèdè Paraguay Lati owo Akinwale Taophic Ogbontarigi ninu boolu alafesegba to je omo bibi orileede Brazil ti o si ti fi igbakan ri je eni...
View ArticleManchester United Ti Se Tán Láti Ra Odion Ighalo Pátápátá
Manchester united ti se tán láti ra Odion Ighalo pátápátá Lati owo Akinwale Taophic Se won ni ti egungun eni ba jo re, ori a ma ya atokun re. Ati wi pe, Ku ise ni n mu ori eni ya! Gudugudu meje ati...
View ArticleAriwo kí ló ń ṣẹlẹ̀ ní Akure ní àwọn ènìyàn fi bọnu!
Ó kéré tán Ilé méjì tí àwọn ènìyàn ń gbé, ilé ẹkọ ati Ilé ìjọsìn ló wó ní ìlú Akure lẹ́yìn tí ìbúgbàmù dún ní ìpínlẹ̀ Ondo. Agbẹnusọ Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Ondo, Tee-Leo Ikoro ló fi ọ̀rọ̀ náà léde...
View ArticleSanwo-olu Máa Fún Ẹgbẹ̀rún Lọ́nà Igba Ènìyàn Lóúnjẹ L’eko
Nipa rogbodiyan ajakale arun coronavirus to n ja kaakiri agbaye to si tun ti rapala wo orileede Naijiria lati bii ose merin seyin. Ijoba ipinle Eko ti ti awon oja ti kii se ti ounje jijie ati mimu....
View ArticleOjúmọ́ Kan, Oògùn Kan
Ilu nla bii orileede Naijiria sowon lagbaye. Ko si odun kan tabi osu kan to le lo lofee ki o ma se si ohun kan ti a maa gbe poori enu. Igba miiran, o le je Obasanjo lo maa ko leta si Aare to maa dogun...
View ArticleÌtànkálẹ̀ Àrùn Coronavirus Nílẹ̀ Amerika Ti Ju Ti Italy Àti China Lọ!
Ìtànkálẹ̀ àrùn Coronavirus nílẹ̀ Amerika ti ju ti Italy àti China lọ! Ìlẹ̀ Amẹ́ríkà mà ti gba ipò kínní gẹ́gẹ́ bí orílẹ̀-èdè tí ìtànkálẹ̀ Coronavirus ti pọ̀jù lọ l’ágbàáyé pẹ̀lú ènìyàn tó lé ní...
View ArticleṢèyí Mákindé, gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní ìpàdé ètò ọrọ̀ aje Nàìjíríà l’òun ti kó...
Bí babaláwo bá ń kígbe ẹ̀fọ́rí, bóyá ni ìrètí aláìsàn kò pin o. Bí Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ṣèyí Mákindé, ní ọjọ́ Ajé ti kéde rẹ̀ fáyé gbọ́ pé òun náà ti dara pọ̀ mọ́ iye àwọn tó ti kó àrùn Coronavirus...
View ArticleÈnìyàn tó ní àrùn coronavirus wọ 131 ní Naijiria
Ènìyàn tó ní àrùn coronavirus wọ 131 ní NaijiriaÌròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí Eniyan ogun lo tun kun awon ti arun coronavirus n ba ja ni orileede yii ni oni ogbon ojo, osu keta odun 2020.Metala ni Eko,...
View ArticleOrí kó ènìyàn márùn-ún yọ lọ́wọ́ coronavirus l’Ekoo
Orí kó ènìyàn márùn-ún yọ lọ́wọ́ coronavirus l’EkooÌròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí Alaisan marun-un ninu awon ti arun buruku covid-19 ti n ba finra lati bii ose meloo kan seyin gba idande. Yoruba bo “won...
View ArticleSeyi Makinde di gómìnà kẹ́ta tó kó àrùn Covid-19
Oni ogbon ojo, osu keta ni ayewo gomina ipinle Oyo, Alagba Seyi Makinde jade, ti ayewo naa si gbee pe o ni arun naa. Oun ni o maa je eleeketa gomina ni orileede yii ti ayewo fihan pe won ni arun...
View ArticleÀwọn agbẹjọ́rò ta ko ìnáwó àti òfin kó-nílé-ó-gbélé Ààrẹ àti àwọn gómìnà
Orisiirisii awon agbejoro ati awon amofin pelu ojogbon lorisiirisii ni won ti n yo suti ete si igbese awon ijoba orileede yii, paapaa julo lori arun coronavirus to gbode. Won ni ko tile tona rara ki...
View ArticleAdarí àgbà ilé ìwòsàn UCH kò ní àrùn Coronavirus mọ́
Họ́wùú! bí babaláwo bá ń kígbe ẹ̀fọ́rí, kín ni yóó jẹ́ àtubọtán aláìsàn? Kò jẹ́ jẹ́ bẹ́ẹ̀. Adarí àgbà ilé ìwòsàn ẹ̀kọ́ṣẹ́, UCH Íbàdàn Ọ̀jọ̀gbọ́n Abiodun Otegbayo ti yiijẹ o, kò ní àrùn Coronavirus mọ́...
View ArticleOgún ènìyàn jàjà bọ́ lọ́wọ́ coronavirus
Ogún ènìyàn jàjà bọ́ lọ́wọ́ coronavirusÌròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí Ni ipinle Eko ni ori ti ko ogun eniyan yo ni ile iwosan ti won ti n toju awon ti kokoro Covid-19 n ba ja. Bi o tile je pe won ni ko...
View ArticleMo Ti Fi Ẹjọ́ Abani Lórúkọjẹ́ Tó Fẹ́ Fi Àwòrán Ìhòòhò Mi S’órí Ìtàkùn Àgbáyé...
À fi kí Ọlọ́run gbani lọ́wọ́ ẹni tó ń ṣọ́ni tá ò ṣọ́ o, ló dífá fún kójú má ríbi,gbogbo ara lòògùn rẹ̀, bí gbajúgbajà olórin wákà, Salawa Abẹni ti sọ pé, òun ti fi ẹjọ́ abani lórúkọ je tó fẹ́ fi...
View ArticleṢeyi Makinde, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Sọ̀rọ̀ Lórí Àrùn Coronavirus Tó Ní
Ìròyìn tó bá ọ̀pọ̀ lẹ́jafùú ni ìròyìn ‘Mo ti ní àrùn Coronavirus’ èyí tí Gómìnà Ṣèyí Mákindé gbé jáde ní ọjọ́ Ajé lójú òpó twitter rẹ̀. Níbáyìí tí ó ti lo ọjọ́ méjì ní ìgbélé lẹ́yìn ìkéde yìí, gómìnà...
View ArticleEwi Toni: Egbe APC iba oooo
Egbe buruku tin fi ebi PaniOdaju egbe tio lanu talakaOmo buruku wole iya re busekun loruko APCEgbe alatako ekun oko PDPEgbe buruku tin fiya je mekunuAlujonu egbe tin Rin Loru ogonjoEgbe odaju tin fun...
View ArticleÀwa kò tíì gba owó ló̩wó̩ e̩niké̩ni – Boss Mustapha
Àwa kò tíì gba owó ló̩wó̩ e̩niké̩ni – Boss Mustapha Ìròyìn láti o̩wó̩ Yìnká Àlàbí Awon igbimo ti ijoba apapo gbe kale lori arun coronavirus ni awon eniyan ti n fi esun inakuna owo kan kaakiri.Eyi lo...
View ArticleÒòlù ìdájọ́ ré bá Fúnkẹ́ Akíndélé àti ọkọ rẹ̀ lẹ́yìn, owó ìtánràn, ìgbélé...
Kò sí n tó burú kí abẹ òfin ba Ògbó Awo tó bá ń se bí ọ̀gbẹ̀rì .Ilé ẹjọ́ ti dá gbajúgbajà òṣèré sinimá, Fúnkẹ́ Akíndélé àti ọkọ rẹ̀ Abdulrasheed Bello lẹ́jọ́ pé ó jẹ̀bi ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn án pé ó...
View Article