Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live

Ààrẹ Buhari ní ààbò wà fún ẹ̀mí ààrẹ́ àná, Goodluck Jonathan

Ààrẹ Buhari ní ààbò wà fún ẹ̀mí ààrẹ́ àná, Goodluck Jonathan Ààrẹ Buhari ti pe Ààrẹ àná, Goodluck Jonathan lórí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀,láti báa kẹ́dùn lórí ìkọlù àwọn agbébọn tó wáyé ní Òtuòkè tíí ṣe ìlú...

View Article


Òlódumarè les bendiga, que tengan una feliz y bendecida tarde.

Ẹ̀là mo yìn bọrú.Ẹ̀là mo yìn bọyè.Ẹ̀là mo yìn bọ’ṣíṣẹ. Òlódumarè les bendiga, que tengan una feliz y bendecida tarde. Ijuba. Doy reverencia. Ìdà kí si ònà ní nse ejó lè yínA’dífá’fún Esin ohun AgboTi...

View Article


Ìjọ Ọ̀rúnmìlà Ifákáyéjọ afi òtítọ́ ayé hàn

Àwa ni ìmọ́lẹ̀ fún gbogbo Ìjọ mímọ́ Ọ̀rúnmìlà ní gbogbo àgbáyé nítorí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tí àńpè ní Ifá ni a fín to Ìjọ tiwa Ifá(ọ̀rọ̀ Ọlọ́run)ni afi kó ayé jọỌ̀rúnmìlà(aṣíwájú rere)ní abá ni táyése Ẹ wá...

View Article

Odù kan gorí àtẹ,Ọdẹ́gbèmí Ọdẹ́gbolá11 goróyè Àràbà nílẹ̀ẹ̀bàdàn

Odù kan gorí àtẹ,Ọdẹ́gbèmí Ọdẹ́gbolá11 goróyè Àràbà nílẹ̀ẹ̀bàdàn Fẹ́mi Akínṣọlá Erin wo! Àràbà Awo ilẹ̀ Ìbàdàn, Ògbó Awo Oyewusi Amọo Fakayode wọ káàl’ẹ̀ sùn.Ọjọ́ a kú là á dère,èèyàn ò sunwọ̀n láàyè....

View Article

Mu pàrágá wakọ̀ l’Ọyọ, kóo kó sí páńpé̩ ìjọba

Mu pàrágá wakọ̀ l’Ọyọ, kóo kó sí gbaga ìjọba Fẹ́mi Akínṣọlá Omi tuntun ti rú, ẹja tuntun ti wọ ọ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Awakọ̀ mẹẹdọgbọn ni ọwọ́ òfin ti tẹ̀ nìpínlẹ̀ náà lórí ẹ̀sùn pé wọ́n ń mutÍ nígbà tí...

View Article


Ohun t’ọ́kùnrin ń ṣe l’Ekiti, obìnrin lè ṣe é. Àjọ̀dún Àṣà ìbílẹ̀ lékìtì

Ohun t’ọ́kùnrin ń ṣe l’Ekiti, obìnrin lè ṣe é.. Àjọ̀dún Àṣà ìbílẹ̀ lékìtì Fẹ́mi Akínṣọlá Àṣà àti ìṣe wà nínú n tíí ṣàfíhàn èèyàn bí ọmọ ọkọ tàbí ọmọ ìdàkejì n ló díá fún bí onírúurú ohun tẹ́ ẹ̀ tilẹ̀...

View Article

Naira Marley ń rìn ní bèbè ẹ̀wọ̀n lọ́dún 2020 bí kò bá fara hàn lórí ẹ̀sùn...

Naira Marley ń rìn ní bèbè ẹ̀wọ̀n lọ́dún 2020 bí kò bá fara hàn lórí ẹ̀sùn ìjọ́kọ̀gbé…..Ilé ẹjọ́ Àdúrà ká má rẹ́jọ́ loníkálukú ń gbà,kí èṣù ó sì má yá wa lò.Ṣùgbọ́n bí nǹkan ṣe ń lọ yìí fún Naira...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àmọ̀tẹ́kùn: Ẹ̀ṣọ́ ilẹ̀ Oòduà (Yorùbá) ‘Àmọ̀tẹ́kùn’ ṣetán láti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́...

Ẹ̀ṣọ́ ilẹ̀ Oòduà (Yorùbá) ‘Àmọ̀tẹ́kùn’ ṣetán láti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ káàkiri ilẹ̀ káàárọ̀ o ò jíire. Àmọ̀tẹ́kùn Ọ̀rọ̀ ti di olójú ò níí yajú ẹ̀ sílẹ̀ kí tàlùbọ̀ ó yíwọ̀ọ́ àti pé ọmọ onílùú kò níí fẹ́ ó tú...

View Article


È̩ ń fi ẹ̀wọ̀n run imú ẹ̀yin Olóyè Ìbàdàn mọ́kànlélógún tẹ ń ǹ pera a yín...

Ọrọ̀ kò tíì tán lórí àwọn Olóyè mọ́kànlélógún tí Ilé ẹjọ́ sọ pé kí wọ́n lọ rọọ́kún nílé nílùú Ìbàdàn. Kọmíṣọ́nnà ètò ìdájọ́ tẹ́lẹ̀rí nípìńlẹ̀ Oyo, Ọ̀gbẹ́ni Michael Lànà ló ṣe ìkìlọ̀ fún wọn pé, kí...

View Article


Ẹjẹ yóó sàn, bí Amẹ́ríkà ṣe pa olórí ọmọ ogun un wa – lran

Ẹjẹ yóó sàn, bí Amẹ́ríkà ṣe pa olórí ọmọ ogun un wa..lran Kójú má ríbi , gbogbo ara lòògùn rẹ̀,bó ṣe jẹ́ pé, ó ń bọ̀ ,ó ń bọ̀ , gbogbo ara ní wọ́n mú tó o.À bí kí lọ̀rọ̀ ogun abẹ́lé kẹta “World War...

View Article

Ẹgbẹ́ Shiites wọ́de l’Abuja, wọ́n jó Àsìá Amẹ́ríkà

Ẹgbẹ́ Shiites wọ́de l’Abuja, wọ́n jó Àsìá Amẹ́ríkà Egbìnrìn ọ̀tẹ̀, bá a se n pàkan, nìkan ń rúÀwọ́n ọmọ ẹgbẹ́ “Islamic Movement of Naigeria” (IMN) tí gbogbo ènìyàn mọ sí Shi’ites lọ́jọ́ ajé ti ya sí...

View Article

Àwọn ará ilú dáná sún èèyàn méjì tí wọ́n furasí bíi olè

Àwọn ará ilú dáná sún èèyàn méjì tí wọ́n furasí bíi olè Ọjọ́ gbogbo n t’olè, ọjọ́ kan n tolóhun.Àwọn ènìyàn méjì kan ti wọ́n fura si gẹ́gẹ́ bi olè, ni wọ́n ti dáná sun nílùú Calabar, tíí ṣe olú ilú...

View Article

Ìjọba ti ayédèrú ilé ọmọ aláìlóbìí pa, ọmọdé mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n gbòmìnira

Ìjọba ti ayédèrú ilé ọmọ aláìlóbìí pa, ọmọdé mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n gbòmìnira Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn aláṣẹ tọ́rọ̀ kan lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti kó àgádágodo sílẹ̀kùn ilé ọmọ aláìóbìí kan tí kò ní wè é òfin ní...

View Article


M C Oluo̩mo̩ fo̩wó̩ o̩lá gbáwa lójú – NURTW

MC Oluo̩mo̩ fo̩wó̩ o̩lá gbáwa lójú – NURTWLáti o̩wó̩ Yínká ÀlàbíOro ti gbogbo ara ilu ni o ti ku regbe ti o si ti di ohun igbagbe ni o tun n rugbo ni ibere ise yii laarin Musiliu Akinsanya ati...

View Article

Transforming Ìṣẹ̀ṣe Temples, Shrines, Houses Of Worship

Women devotees live in a sanctuary that attends to both their spiritual and physical needs at the Àkòdì Òrìṣà. We train them to produce things that can be marketed. Spirituality is great and...

View Article


Iyami And Ipese To Appease Iyami

The Iyami are supernatural women who have been blessed by Elodumare with a great power which can be seen in the Odu Ifa Osetua, where it is written: anyone who makes a plan by excluding from it the...

View Article

Ẹ kéde iye ọlọ́pàá tó gba rìbá, kí ẹ tó má a yin ra a yín… Aráàlú sọ fún...

Ẹ kéde iye ọlọ́pàá tó gba rìbá, kí ẹ tó má a yin ra a yín… Aráàlú sọ fún iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Èsì àwọn ọmọ Nàìjíríà tó tẹ̀lé bí iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ṣe yin ara rẹ̀Lórí káàdì tí wọ́n fi síta lójú òpó ayélujára...

View Article


Ìdí tí nó̩ḿbà ìdánimò̩ kò fi jé̩ dandan mó̩ – Àjo̩ JAMB

Ẹ kò nílò nọńbà ìdánimọ̀ NIN fún ìdánwò àṣewọlé ọdún 2020… Àjọ JAMB Fẹ́mi Akínṣọlá Ni báyìí Àjọ tó ń rí sí ìdánwò àṣewọlé ilé ẹ̀kọ́ gíga JAMB tí kó àfàró nípa lílo nọ́mbà ìdánimọ̀ “NIN” fún ìdánwò...

View Article

Ó ju ẹnu Malami lọ láti ní ètò náà kò bófin mu

Ó ju ẹnu Malami lọ láti ní ètò náà kò bófin mu Kí ojú má ríbi, gbogbo ara lòògùn rẹ̀, èyí ló mú kí Gómìnà ipinlẹ Ọyọ, Ṣèyí Mákindé sáré tètè gba ìlú Abẹokuta lọ, láti lọ ṣèpàdé pọ̀ pẹ̀lú Olóyè...

View Article

Asiwaju Sí Aso̩ Lójú Eégún “Operation Àmò̩té̩kùn” Láti O̩wò̩ Yínká Àlàbí

“Asiwaju sí aso̩ lójú eégún “operation Àmò̩té̩kùn”Láti o̩wò̩ Yínká ÀlàbíAsiwaju Bola Ahmmed Tinubu to je asiwaju agba ninu egbe oselu APC ni gbogbo aye ti n wa kiri lati ojo ti Abubakar Malami ti ni...

View Article
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live