Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live

E ba mi Pari owe yii

View Article


Òṣèré wo ni ẹ fẹ́ràn jù nínú àwọn àgbà osere meji yi?

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Awa Omo Oudua Rere: E Da Epa Owe Kan To Ba Oro Aja Lo

Owe Yoruba

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Gege bi Omo Oodua Rere, Nje E Mo Oruko ti won pe kokoro yi ?

Kini Oruko ti won pe kokoro ti o wa ninu aworan oke yii ?

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ti o ba ka iwe yii fi ara e han

View Article


Fayose kò mo̩ bò̩ò̩lì àti àgbàdo je̩ tó mi,àmó̩… – Fayemi

Gomina ipinle Ekiti, Dr Kayode Fayemi lo n salaye yii nibi eto ori telifison Kan ti arabinrin Morayo Afolabi n dari re.Leyin ti gomina dahun orisiirisii ibeere ni arabinrin naa wa tun beere asepo to...

View Article

Odù Ifá Mímọ́ Ọ̀bàrà Bubu

Ekáàrọ̀ọ́ ẹ̀yin ènìyàn mi, aojiire bi? Oni a sanwa o, ao rí tiwa se loni, gẹ́gẹ́bí òní ṣe jẹ ọjọ́ àíkú, gbogbo wa koni kánjú ku lágbára Olodùmarè àṣẹ.E jékí a fi odù ifá mímọ́ ọ̀bàrà bubu yi ṣe ìwúre...

View Article

Adúmáadán Àjèjé

Ẹmu daada ní ń bẹ nínú aháÒgùrọ̀ àtàtà ní ń bẹ nílẹ̀ akèrèǹgbèỌtí ò dá, àlejò ò lọ!Ẹni ọtí kìí tí AdúmáadánAdúmáadán Àjèjémá gbádùn ara rẹ lọ! ‘Òògùn ibà ni, òògùn ibà ni,’Bí eré, bí eré ìyálé ilé...

View Article


Àmọ̀tẹkùn ni wọn yóó maa pe orúkọ ikọ̀ tó n pèsè ààbò yíká ilẹ̀ Yorùbá –...

Àmọ̀tẹkùn ni wọn yóó maa pe orúkọ ikọ̀ tó n pèsè ààbò yíká ilẹ̀ Yorùbá…..Akerdolu Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe Yoruba bọ ,wọn ni Ogun ti yoo wọle koni,ọna la a tii pade ẹ lo bi ọrọ ti Gomina ipinlẹ Ondo, Rotimi...

View Article


Bàbà wá Lérè paimo pé ọgọ́rin ọdún lónìí (80)

Ẹ jẹ ka jọ gbadura fun Ẹda Onile-ọla pe bi wọn ṣe ṣe tọdun yii ni wọn yoo ṣe tẹẹmi-in towo-tọmọ, ninu ilera pipe ati aiku ti i ṣe baalẹ ọrọ.

View Article

Ọdún orò gbìnà yá, ìdájí ní àwọn olórò yóò fi máa yíde ìlú níṣẹ̀yin

Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe aifẹsọ kebosi,lai rẹni jo o,ati pe n ta o ba fẹ o bajẹ,o ni bi o ṣe yẹ ka ṣe e,eyi lo bi atunse abẹnu lati fopin sawuye wuye to waye latari aawọ to suyọ laarin awọn onisese ati awọn...

View Article

E̩ tu èékánná lára S̩owore – Ilé-e̩jó̩

Ile-ejo giga to fi ikale si ilu Abuja lo pase fun ijoba apapo pe ki won yokun lorun Ogbeni Omoyele Sowore.Sowore ni o n gbimo lati se iwode Kan to maa mi ilu titi. Lati igba naa ni ijoba apapo ti fi...

View Article

Ẹgbẹ ́Afẹ́nifẹ́re kọminú lórí ìwádìí ikú ọmọ Baba Faṣọranti to jẹ olori...

Ẹgbẹ ́Afẹ́nifẹ́re kọminú lórí ìwádìí ikú ọmọ Baba Faṣọranti to jẹ olori Afẹ́nifẹ́re – Odumakin Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà ní bí eyín bá n mì pẹkẹ pẹkẹ,erìgì ni kò fálẹ̀ mójúṣe rẹ̀.Ẹgbe Afenifẹre ti fi...

View Article


Ṣàgbẹ̀lójú yòyò, ni ọ̀pọ̀ àwọn òṣèré…. òjòpagogo

Ṣàgbẹ̀lójú yòyò, ni ọ̀pọ̀ àwọn òṣèré…. òjòpagogo Fẹ́mi Akínṣọlá Awọn agba bọ,wọn ni purọ n niyi,ẹwu ẹtẹ nii da bolowo ẹ lọrun lo mugbajugbaja agba ọjẹ oṣere Yoruba, Razak Ọlayiwọla ti gbogbo eeyan mọ...

View Article

Àrùn burúkú fé̩ tú Queens college

Arun iba buruku kan n da yanpon- yanrin sile bayii ni ile-ise awon obinrin (Queens college) to wa ni ilu Eko.Ironu ti dori awon agba kodo ni ipinle Eko bayii paapaa julo fun gbogbo awon to lomo nibe....

View Article


615″, ńọ́ń́bà tuntun fún ìdáàbòbò àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ̀

“615”, ńọ́ń́bà tuntun fún ìdáàbòbò àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Awọn agba bọ wọn ni oju bayii ni alakan fii sọri.Eyi naa lo mu gomina ipinlẹ Oyo,Ṣeyi Makinde gbe igbesẹ akin, ni bi o ṣe...

View Article

Artist: Moyo Okediji​

My motherWho walks in the nightGraceful be thy stepsAs you place your heelOn the head Of a hidden Cobra And it cannot bite you.

View Article


Ìjàpá Tó Wà Ní Ààfin Ṣọ̀ún Ògbómọ̀ṣọ́ (Alàgbà) Ti Papòdà

Ìṣe èèyàn ,ìṣe ẹranko, Ìjàpá tó wà ní ààfin Ṣọ̀ún Ògbómọ̀ṣọ́ Alàgbà ti papòdà lẹ́ni ojilelọọdunrun ọdún ó lé mẹrin lóke eèpẹ̀ . Fẹ́mi Akínṣọlá Toyin Ajamu, to jẹ akọwe agba ni Ààfin Kabiyesi Ṣọun ti...

View Article

Ilééṣẹ́ Aṣọ́bodè Naijiria ń pa bílíọ̀nù N5.8 wọlé lójúmọ́

Ilééṣẹ́ Aṣọ́bodè Naijiria ń pa bílíọ̀nù N5.8 wọlé lójúmọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe n ta o ba fẹ ba fẹ o bajẹ, o ní ba a ṣe e ṣe e.N lo bi ọrọ kan ti ọ̀ga agba asọbode ilẹ yìí sọ pé,“Naijiria ti n jere pupọ...

View Article

Soworẹ́ Gbòmìnira Láhàmọ́ Ọ́ Dss Pẹ̀lú Ọgọ́rùn Ún Mílíọ̀nù Náírà

Soworẹ́ gbòmìnira láhàmọ́ ọ́ DSS pẹ̀lú ọgọ́rùn ún mílíọ̀nù náírà Fẹ́mi Akínṣọlá Èèyàn téégún ń lé,kó máa rọ́jú,bó ṣe ń rẹ ará ayé,náà ló ń rèrò ọ̀run. Àgbálọ gbábọ̀, ilé ẹjọ́ gíga t’ìjọba àpapọ̀...

View Article
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live