Àwòrán télè ti Leo Babarinde Dasilva nígbà tí ó wà ní omo àgbákórùn.
Àwòrán télè ti Leo Babarinde Dasilva nígbà tí ó wà ní omo àgbákórùn. Ní àná tí se ojóbò tí àwon eléyìbó n pè ni Thursday, won ni kí àwon wo èyìn wò. Ará ilé BBNaija télè tí a mò sí Leo Babarinde...
View ArticleTope Osoba se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún métàlélógbò (33) pèlú...
Temitope Osoba tí gbogbo ènìyàn mò sí Tope Osoba jé òsèré orílè èdè Nìjíríà tí ó sì tún jé olùko eré, won bí i ní ojó kejì osù kejìlá, odún 1985. Ó jé jé akékòó jáde ilé-èkó gíga ifáfitì Olabisi...
View ArticleBánà Omo Egbé APC tí ó n lo fún Gómìnà ìpínlè Kwara ni won lè sí iwájú...
Bánà Omo Egbé APC tí ó n lo fún Gómìnà ìpínlè Kwara ni won lè sí iwájú agboolé àwon Saraki. Ìròyìn kàyéfì… Omo egbé APC tí a mò sí Abdulrasaq Abdulrahman, tí ó n díjé fún ipò Gómìnà ìpínlè Kwara ti se...
View ArticleGómìnà ìpínlè Osun tí a sí Oyetola gba àwon èèyàn là nínú ìjàmbá okò tí ó...
Ókéré jù èèyàn tí ó kojá néjìlá ni ó fara pa nínú ìjàmbá tí ô selè ní òpópónà Ibadan lo sí Èkó sùgbón tí Gómìnà Oyetola ti gba wón kalè. Ògbéni Isiaka Oyetola náà n lo sí èkó ni ojó náà kí ó tó di wípé...
View ArticleMi ò le fé okùnrin tí kò bá le bámi sùn fún wákàtí méjìlá sí méèdógún.
Mi ò le fé okùnrin tí kò bá le bámi sùn fún wákàtí méjìlá sí méèdógún. Arábìnrin kan tí a kò fi taratara mo orúko rè súgbón tí kò le jú omo odún méèdógún sí ogbòn kan ni ó so wípé òun kò le fé okùnrin...
View ArticleÀwon tí ó n gbélè sunkún síta fún ìrànlówó nígbà tí àwon adigunjalè jàwón...
Àwon olùgbé Opolo ní Yenagoa ìpínlè Bayelsa ni ìbèrùbojo ti gba okàn won léyìn tí àwon adigunjalè jà won lólè tán. Gégé bí ìròyìn se so, àwon olè yí kojá ogbòn tí won sì gbé àwon ohun ìjà olóró lówó...
View ArticleAsiri àwo kintú,
Asiri ẹ̀tú kintú, Iwọ iwori bógbè IFA, Ki owá bo asiri mi, Iwọ iwori bógbè. Mogbá ládùrá wipè loni ọjọ àbámẹtá asiri gbógbó wa koni tu kotobó lailai,gbogbo abá ti aba da loni yio jẹ mimusẹ, Aṣẹ̀ aṣẹ̀...
View ArticleỌmọ: Ẹ̀bùn Edùmarè !
Ẹ̀bùn Edùmarè ni ọmọ Ẹ̀rí ìfẹ́ rẹ̀ sí wa ni wọ́n Èdùmàrè à ń bẹ̀ ọ́ Bá wa wo àwọn èwe yè Fi wọ́n fún àwọn tí ń wojú rẹ fún ẹ̀bùn wọn Má ṣe jẹ́ kí wọ́n kú mọ́ àwọn òbí wọn lọ́wọ́ Èyí a wí yìí, kárọ̀...
View ArticleBí ewúrẹ́ bá bojú wo ẹ̀yìn
Á fi èpè fún elépè Mo sé ní ìwúre wípé gbogbo ọ̀tá tí o bá ń robi tàbí sebi sí èmi àti ẹ̀yin lẹ́yìn yoo ma fí orí ara wọn gbe láṣẹ Ọlọ́run Olódùmarè Àsẹ Eu oro para que qualquer inimigo planeje o mal...
View ArticleẸ Káàbọ̀ sí oṣù tuntun
Oṣù Òkúdù á yanjú gbogbo ohun tí ó ń dùn wá lọ́kàn Ẹnikẹ́ni ò sì ní bá wa du’re ayọ̀ wa. @AlamojaYoruba
View ArticleIfá naa ki bayi wipe: Osa Alawure (Osa Otura) – Otua Meji
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isinmi ana o, adura wa yio gba, ori buruku koni je tiwa loni o Àse.Mo nfi akoko yi nki gbogbo onisese patapata kaakiri agbaye wipe aku aseyori odun ifá agbaye o...
View ArticleẸ̀yẹ̀lé
Yiyẹ̀ lonyẹ́ ẹ̀yẹ̀lé, Ayé ayẹ̀ wá kàlẹ̀, Rirọ lonrọ àdábà lọrún, Ayé yio rọrún fún wá jẹ̀, Tùtù ni omi àfi owúrọ̀ pònri, Ao ni mo inira layé ti àwá, Alanú kàn toju igba àlànú lọ, Yio wa wari, Mogbà...
View ArticleTàgiiri
Tàgiiri ma yí nìsóAra rẹ lokùn Ara rẹ ní ajé gbe ńso Gbogbo ara tàgiiri fín so ajé Mo wá se ìwúre lo ní wípé ire owó yoo ma wọlé wa wa ooooGbogbo iṣẹ́ tí abá se,owó rẹpẹtẹ ní a o ma rí ní èrè láṣẹ...
View ArticleNí Ojúmọ́ Ọjọ́ Àbámẹ́ta Tòní – #Kojoda #Yoruba #Orisa
Òsùn gbó ríró, kí o má dubúlẹ̀Òòró gangan laa bósùnÒsùn dé o Alàwòrò Ọlọ́run ọba ma jẹ kí gbogbo wa saarẹ Mo sé ní ìwúre fun orí kọ̀ọ̀kan wa ní ojúmọ́ ọjọ́ Àbámẹ́ta tòní wípé àìsàn kéré tóbi aráyé kò...
View ArticleIfá naa ki bayi wípé..
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o Eledumare ninu aanu re yio fi ire gbogbo wa wari loni o Àse.Ifá yi gbawa niyanju wipe ki a bo ifá pelu obi meji ati agbebo adiye, ki a si se akose ifá...
View ArticleKọ́kọ́rọ́ ayọ̀ mi: Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ !
Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ Ènìyàn ò daWọ́n lè sọ́ sómi Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun tòní wípé kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ èmi àti ẹ̀yin, Ọlọ́run ọba kò ní fí le ọ̀tá lọ́wọ́ o. Kọ́kọ́rọ́ Ayọ̀ wa kò ní bọ́ só mi. Àsẹ
View ArticleIfá naa ki bayi wípé…
Ifá gba gbogbo akápò re niyanju wípé ki won o rubo nitori ki a baa le ri orí ayé wa, ki a baa le de ile ileri, ifá ni nkan yio soro tabi le die fun awon ti won ba koti ogboin sebo, ifá ni atirise tabi...
View ArticleOdu Ifa,”Irosun Oyeku” Cast Today For Ose Ifa
Looking at Odu Ifa, “Irosun Oyeku” cast today for Ose Ifa, I can advise all Priests and Priestesses to imbibe calmness in their characters so that they can always achieve their desires. Secondly, the...
View ArticleẸyọ De Ọlọ́bẹ̀ Oko
Ọ̀̀rọ̀ mi gbogbo ka sàì yọ́ ikin nínú gẹ̀ẹ̀rẹ̀gẹ̀ Mo sé ní ìwúre ní ojúmọ́ tòní wípé gbogbo ẹ̀sẹ̀ tí a sẹ̀ Ọlọ́run, osó,ajẹ́ àbí ènìyàn bi tiwa ni, tó ń fa ìdíwọ́ kan àbí ìkejì, mo súre fún wa kí...
View Article