Arákùnrin kan ni ó kú sínú odò nígbà tí ó sòrò nípa èmí òkúnkún.
Arákùnrin tí ó n gbé ní Èkó ni ó kú nígbà tí ó lo kí ègbón rè ní Ujeme, Ekpoma, ìpínlè Edo, ní won ti rí òkú rè nínú odò ní ilé rè, léyìn tí a gbó wípé ó sonù. Gégé bí ìròyìn se so, ègbón olóògbé so...
View ArticleÀwon arákúnrin méjì kan jà lórí eni tí yóò jókòó sí iwájú okò.
Àwon èrò méjì ni a rí lónìí tí won n jà látàrí eni tí yóò jóko sí iwájú oko ní Èkó . Nígbà tí ó yá ni awakò ti awon méjèèjì jábó látàrí bí won se n se bí eni tí kò ní opolo. Kò kúkú sí ohun tí a kò ní...
View ArticleGómìnà Arégbésolá fún àwon olùkó ní èbùn okò àti àwon èbùn míràn.
Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Rauf Aregbesola lo sí àjo àwon ilé-èkó àwon alákóbèrè pèlú àwon adarí míràn tí won péjú sìbè láti pín okò fún àwon òsìsé. Kìí se okò níkan ni ó fún won o bí kò se wípé ó...
View ArticleÌpínlè Osun, Ìpínlè Omolúàbí yóò yan ìpín won lónìí, ojó Àbáméta nígbà tí won...
Gégé bí a ti mò wípé òní tí ó jé Ojó Àbáméta ni ìpínlè Osun yóò dìbó fún ènìyàn tí won fé kí ó di aláse lórí won. Egbé kòòkan sì ti fi omo egbé sílè . Gboyega Oyetola ni ó dúró fún egbé oní ìgbálè tí a...
View ArticleỌmùtí Gbàgbé Ìṣẹ́ (Ìrònú Ọlọtí)
Ilé ọlọ́ti ni ilé ìtura, ibẹ̀ ni àwọn ọ̀rẹ́ ti npàdé fàájì Ibẹ̀ náà ni àwọn èké, àti ọ̀dàlẹ̀ tin pàdé ara wọn Ti ọti bá wọra tán, ara a sì rọ̀ wọ́n pẹ̀sẹ̀,...
View ArticleÀwòrán kí ó tó di onó ìgbéyàwó ti olópàá kan àti olùwòsàn.
Gégé se gégé, onígègè tó pàdé asòpá ni òr olópàá àti olùwòsàn yí jé, bí olópàá bá kojú dogun tí ó sì pa lára, olùwòsàn tí ó jé ìyàwó rè yóò sì ba wò ó sàn . Àwòrán ti aya tí ó n bò lónà àti oko rè, tí...
View ArticleBukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná.
Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná. Ààre ilé ìgbìmò Asòfin tí a mò sí Dókítà Abubakar Bukola Saraki ní àná tí lo kí omo egbé oní àbùradà tí a mò sí egbé PDP, èyí tí egbé yàn láti...
View ArticleTiwa Savage kúnlè kí ògá Shínà peter
Obìnrin àkókó ní inú egbé Marvin kúnlè wò ní orí ìkúnlè nígbà tí ó kí ògà gun àti ògbóntàgirigì tí a mò sí Shina Peter nígbà tí won n sí ilé-isé pefume brand, Sappire Scent ní Lenox mall ní ìpínlè Eko....
View ArticleOmokùnrin odún métàlá (13) ni àwon olópàá ti mú látàrí ìbèrú tí ó ní sí won.
Omokúnrin kékeré kan ní won ti mó’ lé ní àgó olópàá látàrí ìbèrù tí ó ní fún àwon olópàá. Gégé bí ìròyìn se so, omokùnrin odún métàlá, tí ó sí jé olórí okúnrin ilé-èkó won, ni ó n pon omi lówó nínú...
View ArticleÀwòrán ará ilé Bbnaija télè tí a mò sí Alex, ìyá rè àti ìyá ìyá rè.
Àwòrán ará ilé Bbnaija télè tí a mò sí Alex, ìyá rè àti ìyá ìyá rè. Alex Asogwa pín àwòrán rè tí ó rewà àti ti ìyá rè àti ìyá ìyá rè tí ó rewà, ìran méta tí ó rewà púpò. Àwòrán yí mà rewà púpò, ìran...
View ArticleÒtúrá Òfún (Òtúráfùnún)
Àkúsàba Àyàndà Awo ilé Olúmẹ̀ri Àápáálá Ọmọ ilé san wón ó joko lọ Níjọ́ tí ń ṣọ̀gbọ̀gbọ̀ àrùn Tí ń najú aláì le dìde Olúmẹ̀ri Àápáálá làrùn ń ṣe Òún wá á le gbádùn gbogbo nǹkan òun lójú ayé òun báyìí?...
View ArticleÒrò ìsítí gbó òréëwa?
Òrò ìsítí gbó òréëwa? -O féékú wàákú, Ìwõ ò fèékú wàákú sugbon kini kan lèmi fë kio mø daju, Sé nigba tó o wásí ile-aye sé kii sepé àrà(Wonder) ku mó ë ninu. Àrà tóò gbéwá silé ayé tóò ló, tíò...
View ArticleÀwon àjo tí ó n mójú tó ètò ìdìbó tí a mò sí INEC ti kéde Gboyega Oyetola...
Àwon àjo tí ó n mójú tó ètò ìdìbó tí a mò sí INEC ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbà orókè níbi ìdìbò tí won tún dì ní àná. Omo egbé oní ìgbálè tí won fà kalè láti lo fún Gómìnà, egbé tí a...
View ArticleÀwòrán Ìlú Abeokuta nígbà tí a wò ó láti orí òkè olúmo (olumo rock).
Òkè olúmo jé òkè kan gbòógì tí a kò le fi owó ró séyìn nínú àwon òkè tí n be ní orílè èdè Nìjíríà, kìí wá se orílè èdè yí nìkan ni a kò tile fi owó ro séyìn bí kò se wípé káàkiri ilè Adúláwò. Orí òkè...
View ArticleÈ má jé kì olá èro ayélujára tàn yín je- báyìí ni Joke Silva wí.
Nínú ìfòròwánilénuwò nínú ìwé ìròyìn ti Genevieve Nnaji tí won se fún ognóntàrigì òsèré orí ìtàgé tí a mò sí Joke Silva, ni ó ti gba àwon èèyàn ní ìmòràn kí won má se jé kí ohun tí àwon elégbé òhun máa...
View ArticleYorùbá dún
Hà à à!! Elédùmàrè ìgbà wo l’ènìyàn yόò to bo nínú hílàhílo òde ayé yìí nà? Ki baálé ilé jáde láti òwúrò kùtùkùtù àná kό sí ma b’ojú wéhìn wo, Ǹjé irú ìwà béè daa?? Àmò sà à!! Èyí tà á se sikù, Ohun...
View ArticleÀnto Lecky wo Ejò rògbòdò yíká orún rè
Ará ilé Bbnaija télè tí a mò so Anto ti gbé àrà òtun yo fún àwon olólùfé rè, nígbà tí ó lo sí àgbàlà ejò rògbòdò ní orílè èdè Republic of Benin. Ó ko síbè wípé: ” Ní àgbàlá ejò nlá nígbà tí mo rin ìrìn...
View ArticleStephanie Hornecker wo aso tí oyàn rè n hàn feere níbè, tí ó sì dàbí egbin...
Stephanie Hornecker wo aso tí oyàn rè n hàn feere níbè, tí ó sì dàbí egbin nínú è. Arewà télè tí ó tún jé òsèré orí ìtàgé sùgbón tí ó ti di Olùwòsàn báyìí, Regina Askia pín àwòrán tí ó rewà ti omo rè...
View ArticleEjìnrìn Wọ̀jọ ̀wọ̀jọ̀
Ejìnrìn wọ̀jọ ̀wọ̀jọ̀ Awo Ọlọ́wọ̀ ló ṣefá fún Ọlọ́wọ̀ Eléyìí tí yóò roko roko tí yóò gbé kílìṣí tíí ṣe yèyé ajé wálé Ìji lẹ́lẹ́ – Awo Ìji lẹ́lẹ́ Ìji lẹ̀lẹ̀ – Awo Ìji lẹ̀lẹ̀ Ẹ̀fúùfù lẹ̀lẹ̀ ní jági...
View ArticleÒgúndá Ọ̀wọ́nrín (Ògúndẹ̀rín)
Àtẹ́lẹwọ́ mi ọ̀tún ni mo fi kọ́’fá ń dídá Mo mọ Ifá ń dídá A dífá fún Akítán tíí ṣe ọmọ’yè Oníkàá Àtẹ́lẹwọ́ mi òsì ni mo fi kọ́bò ní gbígbà Mo mọ ìbò ni gbígbà Dífá fá fún Aṣọ̀gbà tíí ṣe ọmọ Ẹkùn ni...
View Article