Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live

ÌȘẸLẸ̀ INÁ NÍ BÁGÀ

Hàáààà!!! Iná ooooooo. Iná pupa bẹ́lẹ́ńjẹ́. Bẹ́lẹ́ńjẹ́ bẹ̀lẹ̀ǹjẹ̀ bẹ́lẹ́ńjẹ́. Bẹ́lẹ́ńjẹ́ pupa arańta. Iná gorí òrùlé tán; Ó wá fẹjú kẹkẹẹkẹ. Ìpínlẹ̀ Èkó gb’àlejò iná ńlá. L’ágbègbè Òjòdú Bágà. Ó kọjá...

View Article


The sensiotics of autism were disclosed by Ifa through the sacred Odu Osa...

Osa Oturupon speaks about an emotional disease that manifests through different mechanisms. First of all there is a scattered kinestesis. Kinestesis is characterized by the divergence of many...

View Article


A kú àmójúbà *Osù Agemo (July)

Bí a se wonú osù yìí, a kò níí se gégé ibi, ibi kò níí se gégé wa. Ikú iwájú tó ñ pa wón, odò èyìn tó ñ gbé won ón lo, Oba Adédàá kò níí ka ìpín òkóòkan wa mó irú re. Ní ojó tí ebi bá ñ pa ilé, a kò...

View Article

ITAN ORANMIYAN BABA NLA GBOGBO YORUBA AWON EYA TO WA NILE TABI ORILEDE ODUA

ITAN ORANMIYAN BABA NLA GBOGBO YORUBA AWON EYA TO WA NILE TABI ORILEDE ODUA Loni opo enia mo nro pe gbogbo awa ti awa ni ipinle mefa yi Oyo, Osun, Ogun, Ondo, Ekiti, Eko pelu ipinle Kwara to nka ara...

View Article

Àwon Akékòó Ogbà Fémi jà fún ètó won

Bí a bá pè é ní ìjà láàrin akékòó eka èkó gèésì (Department of English ) àti ti àwon eka èkó nípa òfin (faculty of law) ti ilé-èkó gíga ifáfitì ti Obafemi Awolowo university wo ìyá ìjàkadì Látàrí wípé...

View Article


ỌJỌ́ NÁÀ RÈÉ BÍ ÀNÁ

  Ọjọ́ náà rèé bí àná. Bí eré bí àwàdà; Kánmọ́kánmọ́ l’ọjọ́ ń șí lọ bí ẹyẹ. Ọjọ́ náà rèé bí àná; Tá a bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ ìrìn-àjò ọ̀hún. Òjòó rọ̀ wọ̀wọ̀. Afẹ́fẹ́ fẹ́ ilẹ́lẹ́-ilẹ́lẹ́. Ẹ̀fúùfùlẹ̀lẹ̀ẹ́ m’igi...

View Article

Odun odun kan ko dun dun

Ko dun bi odun yi ri Odun ti o dun ni odun ominira1960 Odun n dun ni dundun n dun Orile-ede ti n San fun wara ati oyin Orile-ede abinibi Nigeria Adugbo ti n toro omo ale ni ke ti i dagba Ki lode ti iku...

View Article

Wizkid àti ìyá rè ya àwòrán papò.

Gbajúgbajà olórin afé tí a mò sí starboy, tí Óní tún jé Wizkid ya àwòrán pèlú ìyá rè. Èyí wùwá ooo.

View Article


Àgbàrá òjò gbé èèyàn méjì lo ní UNN, Nsukka, tí ó sì pa wón.

Èèyàn méjì òtòtò ni ó di olóògbé látàrí àgbàrá òjò tí Ó gbé won lo, tí Óní sì pa wón sí gbàgede enu àbáwolé ilé-èkó gíga ifáfitì ti orílè èdè Nìjíríà, Nsukka (UNN). Gégé bí ìròyìn se so àwon olóògbé yí...

View Article


Tboss se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè Roman

Tboss se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè Roman. Ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Tokunbo Idowu tí ìnagije rè ń jé Tboss, ti se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè Roman. Ó pín àwòrán òun àti...

View Article

Ìgbeyàwó alárédè ti DJ consequences àti Olayemisi Williams. Arákùnrin tí ó ń...

Arákùnrin tí ó ń se isé DJ tí a mò sí DJ consequences àti aya rè Olayemisi Williams ti se ayeye ìgbeyàwó won. A kí tokotayà kú oríre .

View Article

Àwon ìbeta tí ó rewà yí tí ewà won sì wuni yí se ayeye ojó ìbí won pèlú...

John, Peter àti Jamie Obidiegwu, ìbeta se ayeye ojó ìbí won ní àrà òtò. Ayeye ojó ìbí míràn ni ó jé fún àwon ìbeta tí ó jé okùnrin yí, ohun ayò ni ayeye yí sì jé fún won tí won fi se ayeye ojó ìbí won....

View Article

Ogbón kò kúkú ní tán n’ílé ayé kí á wa lo sí òde òrun.

Ogbón kò kúkú ní tán n’ílé ayé kí á wa lo sí òde òrun. Arákùnrin kan ni ó so àwon táyà okò tí ó ti bàjé yí di tábìlì aláfé, okùnrin yí tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà. Kí ní òhún sì rewà.

View Article


AJE NIMO FẸẸ!

. AJE NIMO FẸẸ! Ohun aje f’oju miri ẹnu o le sọ; Oju miri to lori ọrọ aje; Owo(business) f’ẹgbin rẹmi lara; Ninu ẹgbin lọla fiṣe ile; Ọrọ kobakungbe inu iṣẹ-aje ni ngbe. Aje ogugu ni sọ; Onisọ iboji o;...

View Article

Ojó mánigbàgbé ní ilé-èkó gíga Obafemi Awolowo university (OAU).

Ojó mánigbàgbé ní ilé-èkó gíga Obafemi Awolowo university (OAU). Ìsèlè burúkú gbáà ní Óní selè ní ojó kewàá osù keje odún 1999 ní ilé-èkó gíga ifáfitì Obafemi Awolowo university nígbà tí èmi oní inú...

View Article


Irú kí ni eléyìí báyìí, àfi kí olúwa olódùmarè .

Nìjíríà àfi kí olórun gbà wá lówó gbogbo hílàhílo tí ó ń selè yí, irú kí leléyìí báyìí . Eléyìí ló selè ní Oghara. arábìnrin kan ni ó ún gun òkadà lo tí ó sì gbé epo beetíròlù séyìn nígbà tí okò tí a...

View Article

Awada Toni: Omo Ibadan

View Article


Grace Oyelude, obìnrin àkókó tí Ó kókó gba àmì èye omidan arewà ní orílè èdè...

Grace Oyelude, obìnrin àkókó tí Ó kókó gba àmì èye omidan arewà ní orílè èdè Nìjíríà. Ìyáawa Grace Atinuke, tí won bí ní ojó kerìndínlógún osù beelu ní odún 1931, tí a mò sí eni tí ó kókó gba àmì èye...

View Article

Alágemo tó se jéjé ikú pa á.

Kí á dijú ká se bí eni tí ó kú kí á wo eni tí yó se ìdárò eni Ká fi esè ko gbàù kí á wo eni tí yó seni pèlé Ayé laó ti mo eni tí ó ń fé teni Ayé La Ó ti mo èèyàn àtàtà Nítorí ojú larí kòdénú Ìbá jé...

View Article

Àwòrán Saraki nígbà tí won se ìpàdé pèlú Woke, Ortom àti àwon míràn ni ìpínlè...

Àwon ìgbìmò tuntun rè é, Gómìnà ìpínlè River, Nyesom Ezenwo Wike tètè dé sí Ilorin ní ìpínlè Kwara fún ìpàdé pàtàkí náà pèlú àwon ti Benue náà, Gómìnà Samuel Ortom tí ó sèsè ko ìwé láti fi egbé APC...

View Article
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live