A kú àmójúbà *Osù Ebibi (May) tuntun.
A kú àmójúbà *Osù Ebibi (May) tuntun.* Osù ìségun àséwolè ni yóò jé. A kò níí se gégé ibi, béè ni ìkònà burúkú kò níí kò wá. Nínú Osù yìí, a ó ségun òtá ilé àti tòde, a ó réyìn àwon...
View Article*ORIN ORILE EDE NAIJIRIA NI EDE YORÙBÁ*
ESE KINNI_ Dìde Èyin Ará Waká jé ipe Nàijíríà K’à fife sin ‘lè wá Pel’ókun àt’sígbàgbó Kìse Àwon Àkoni wá, kò máse já s’ásán K’à sin t’òkan tará Ilé t’ómìnira,àt’àláfíà So d’òkan. *ESE KEJI* Olórun...
View ArticleSANGO, kABIYESI O!!! LALU OBA KOSO ORIKI SANGO.
Olúkòso! Atu wón ka níbi wón gbé ‘ndáná iró. A lé Babaláwo máa dúró kó Ifá, À ti lójò àti lérùn, Kò séni tí Sàngó kò lè pa. À f’eni tí kogílá kolù, À f’eni tí Esù ‘nse, Ló máa fé kolù Esù. Ló máa fé...
View ArticleOríkì Òsun
Òsun sègèsé olórìyà iyùn Awede kí ó tó we’mo Òsun eléyinjú àánú Igbómolè obìnrin Òsaàyò m’olè Òmómó t’enu m’olè Ayaba bìnrin òtòrò èfòn n’ílé ìyá olúgbón Won kò gbodò m’awo Ìran Arèsà Won kò gbodò...
View ArticleORÍKÌ OFA
Otunba Ikanni: Iyeru okin olofa mojo, Omo olalomi, omo a basu Jo o ko Omo la a re, bu u re, Okan o gbodo jukan, Bokan bajukan Nile olofa mojo, Ogun Oba ni i kowon ni roro, IJA kan IJA kan, Ti won ja...
View ArticleORIKI ILORIN Ilorin afonja.
ORIKI ILORIN Ilorin afonja enudunjuyo Ilu to jinna s’ina To sunmon alujana bi aresepa Ilu tobi to yen,won o leegun rara Esin l’egungun ile baba won Akewugberu ni won A s’adura gbore Aji fi kalamu da...
View ArticleÀfi kí á ma dúpé.
Àfi kí á ma dúpé . Ìwo tí o wà láyé Tí ò ń jeun àsìkò Tí o tún ń wo aso àsìkò Ó tó kí olúwa rè sopé Olúwa tún wá ba o se é Ó tún fún o n’ílé kó,ó ye kí ó dúpé Ó tún ra okò bògìní tó tún l’óyé nínú o jé...
View ArticleYoruba Esu & European Satan: What a generational Colloquial misconceptions !
Satan is an European language and it’s best interpreted by the same European people. Conceptually, in Yoruba culture, ESU and Satan remains different in meaning and does not mean the same. While Satan...
View ArticleAalo apamo Toni: Itan aja ati ijapa!
Alo ooooooo, alo oooooooo. Itan aja ati ijapa. Ni ojo kan iyan mu ni ilu kan, ko si onuje, baba agbe kan wa, to je ipe ohun ni kan ni o gbin n kan si oko re. Ti awon ara ilu ma fi n ri onuje je. Ni ojo...
View ArticleIfa naa ki bayi wipe: Emi ote, Iwo ote
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin ku ose ifá toni, emin wa yio se pupo re laye ase. Gegebi a se mo wípé oni ni ose ifá, e jeki a fi odù ifá mimo eji elemere yi se iwure ti aaro...
View ArticleIwure Ori
Orí mi, gbe mi o! (My Orí, support me) Ori lo da mi (Ori is my Creator) Eniyan ko o (It is not man) Olodumare ni (It is Olodumare) Ori lo da mi (Ori is my Creator) Ori Onise (Ori, the competent...
View ArticleA o ni ri ogun aisan
A o ni r’ogun aisan! Ifa ni: Pere ni tewe iyeye, aloye ni ti peregun; Piri l’eye olongo n ji; A kii b’okunrun eye lori ite; Gege lowu alantakun n fuye; Ota kii ku, ota kii run; Koko lara ota n le;...
View ArticleSùúrù lógbà.
Ìsé kìí se ohun àmúseré Ìyà kìí se ohun àmúsàwàdà Ebi ń pamí kìí mérìń p’ani Sebí ebi kìí w’onú Kí òrò míràn wòó Ojú tí ń kúkú pón isin Kìí se àpón ku Bí kòse àpónlà Bówù kópé títí Ìyà ayé eni ń bò wá...
View ArticleKemi Olunloyo so báyìí wípé! Àwòkóse burúkú gbáà ni Linda Ikeji àtiwípé òun...
Kemi Olunloyo so báyìí wípé! Àwòkóse burúkú gbáà ni Linda Ikeji àtiwípé òun ni àwòkóse rere.OK olunloyo so òpòlopò àsírí nípa oyún inú Linda Ikeji àti nípa ara rè pàápàá. Àtiwípé Linda Ikeji ti kó bá...
View ArticlePaul Okoye níbi tí ó ti ń bá àwon ìbejì rè Nadia àti Nathan seré .
Paul Okoye tí a mò sí Rude boy ni ó pín àwòrán tí ó rewà yí nígbà tí ó ń lo àsìkò pàtàkì pèlú àwon ìbejì rè Nadia àti Nathan seré èyí tí ó pín sí orí èro ayélujára (instagram)..
View ArticleÒdókùnrin kan ní àwon olópàá yin ìbon pa nígbà tí won fé parí ìjà ní Ajegunle.
Òdókùnrin kan tí a gbó wípé ó jé omo ogún odún ni a gbó wípé won fi èsùn kàn àwon olópàá Látàrí ìbon tí won yìn pa Òdókùnrin yí, nígbà tí won ń parí ìjà lówó láàrin àwon ìkò ológun méjì ní agbègbè...
View ArticleFúlàní darandaran pa àwon èèyàn ní ojú ònà Makarda ní òpópónà Makarda.
Óní òun so gbangba gbàngbà ni Láì bèrù enikéni :báyìí ni Adamu Donald Dekwagh, wípé enikéni kò gbodò sùn nígbà tí igbákejì Ààre orílè èdè lo kí won ní Benue ní ànà yí tí àwon wòólì méjì àti darandaran...
View ArticleÀwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó tokotayà yí ti won pàdé nígbà tí won ń sin...
Arábìnrin Nìjíríà kan tí a mò sí Rosemary nípa eni tí yó sèsè di oko rè Láìpé odún màrún-ùn séyìn, nígbà tí won ń sin orílè èdè won lówó ní Kaduna ti pín àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won. Wón dìjo wo...
View ArticleA kú òsè jàkúta.
Sango oooo Olukoso ayanran ina Ina loju, ina lenu Sangiri, lagiri Olagiripapa figba edun bo Eefin ina la n da laye Ina nbe lodo oko mi lorun Abaabe ooooooooo Abaabe laba Se fun SANGO Emi Se SANGO...
View Article