Àwon ará ìlú dojú ìjà ko àwon Fúlàní ní Numan, Adamawa wón pa...
Gégé bí Sani tí ó pin se so, àwon èèyàn Bachama ní alé àná ti dojú ìjà ko àwon fúlàní ní ilé tí won ngbé ní Kwadam Shafaran ìlú kéréje kan ní Numan ti ìpínlè Adamawa. Ó kéré jù márùnlélógójì (45) ni...
View ArticleÌyá omo Davido, Amanda, ti se ayeye ojó ìbí fún Davido nígbà tí ó pé odún...
Amanda, tí ó n gbé ní Atlanta tí ó jé ìyá omo olórin orílè èdè Nàíjíríà, Davido, pin sí orí ìtàn èro ayélujára (insta-story)láti se ayeye ojó ìbí Davido nígbà tí ó pé odún márùnlélógún.
View ArticleEjò nlá kan (paramólè) tí won pa ní agbègbè mi láìpé ní àró yí.
Ní àárò yí nígbà tí mo ti setán láti ma lo sí ibi isé ni mo pàdé àwon ògbéni yí, tí won n yo látàrí wípé won pa ejò, tí mo rò wípé paramólè ni, tí won sì ti gbèrò láti sè je . Ó ti è ti pé tí mo ti fi...
View ArticleÀwon egbé òkùnkùn Badoo ti pa Ebí tí ó jé méta ní Epe ní ìpínlè Eko .
Àwon omo egbé òkùnkùn tí pa ebí tí ó jé méta tí won sì fi omo kékeré tí ó fi ara pa sílè ní Epe ní ìpínlè Eko. Won ti pa gbogbo ìdílé kan run sùgbón won fi omo kékeré kan tí ó pa l’ára gan sílè ní Epe...
View ArticleÒdókùnrin yí ni ó ko “666” sí iwájú orí rè.
Bóyá láti jé kí àwon òré rè lórí èro ayélujára(Facebook) tèka wípé àwon féràn rè ni tàbí kí ó fi di gbajúgbajà. Òdókùnrin tí kò dàgbà jù, tí ó sì jé ò n lò èro ayélujára(Facebook), tí a mò sí Samuel...
View ArticleOta ìbon tí àwon olópàá àti àwon ìgárá olóshà n yìn mó ara won sè sì bá awa...
Oní kèké kan ní PortHarcourt ni ó ti kú látàrí ota ìbon tí ó se sì ta ba nígbà tí àwon ìgárá olóshà àti olópàá n yin ìbon mó ara won. Òdókùnrin tí ó jé oní kèké yí tí ó wá láti ìpínlè Ebonyi ti kú...
View ArticleÀwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí Nosakhare Ogbemudia àti Ekan Egonmwa yà.
Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó omobìnrin olóògbé Dr Samuel Ogbemudia, Nosakhare. Nosakhare, arewà omo Gómìnà àwon ológun ti ìwò oòrùn télè, olóògbé Dr Samuel Ogbemudi, ti setán láti se ìgbéyàwó pèlú...
View Article” Mi ò l’óyún” Tiwa Savage so béè láti dékun ìròyìn tí kò múná dóko tí won n...
” Mi ò l’óyún” Tiwa Savage so béè láti dékun ìròyìn tí kò múná dóko tí won n so nípa rè. Ìròyìn tí ó gbòde kan láìpé ni wípé Tiwa Savage ti l’óyún tí Linda Ikeji so súgbón Tiwa Savage ti dékun ìròyìn...
View Articleolópàá kan ní Enugu ti mú àwon òdóbìnrin méjì nígbà tí won n rìn l’ójú ònà...
Gégé bí eni tí ojú rè to se so, tí ó sì gbe sí orí èro ayélujára se so, olópàá kan ní ìpínlè Enugu ni a ti fi èsùn kàn wípé ó mú àwon òdóbìnrin méjì tí won wò aso ìwòkuwò. A gbó wípé ìsèlè yí selè ní...
View ArticleJuliet Ibrahim ti fé Iceberg Slim won sì ti se ìgbéyàwó ní kóòtù .
Juliet Ibrahim ti fé Iceberg Slim won sì ti se ìgbéyàwó ní kóòtù . Afòròdárà (rapper) tí ó n jé Iceberg Slim àti òsèré bìnrin Juliet Ibrahim ti so ìfé won pò pèlú ìfenukonu léyìn tí won ti se ìgbéyàwó...
View ArticleGomina Obiano lo kí Ààre Buhari ní Abuja léyìn tí ó gbégbà orókè níbi ètò...
Gómìná ti ìpínlè Anambra tuntun, Gómìnà Willie Obiano ní ojó etì (Friday ) ti lo kí Ààre Muhammadu Buhari ní ilé-ìjoba ní ìlú Abuja. Obiano ti dúpé lówó Buhari nítorí kò se àgàbà-n-gebè níbi ètò ìdìbò...
View ArticleIyabo Ojo dùn nínú aso tí kò bo ìdodo (crop top) tí ó wò.
Ògbó-n-tarìgì òsèré, Iyabo Ojo ti gbe lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti àwòrán ara rè nígbà tí ó ti pé ogójì odún tán , ó sì tún fi hàn wípé dunú. Òsèré Iyabo Ojo, yó se ayeye ogójì (40) odún...
View ArticleÀwon òrébìnrin tí ó lóyún ní ìgba kan náà ni won ya àwòrán pèlú oyún won.
Àwon òrébìnrin tí ó lóyún ní ìgba kan náà ni won ya àwòrán pèlú oyún won. Eléyìí ma ti è wuni won sì rewà pèlú oyún won papò. Mo ro wípé oyún kìí mú àwon èlòmíràn rewà ni, bí ti àwon eléyìí kó, won Jo...
View ArticleArábìnrin yí se ayeye ojó-ìbí fún omo òdò rè ní àrà òtò.
Èyin obìnrin n’ílé, èèyàn mélòó ni ó le se eléyìí fún omo òdò rè. Omodé yí àti olówó rè rè é nínú àwòrán yí, àná ni ojó ìbí rè. E jòwó obìnrin mélòó ni ó tún le se èyí fún omo òdò rè.
View ArticleMaryam Sanda ti sun ekún àsun-n-dáké nígbà tí won gbe lo sí ilé-ejó látàrí...
Maryam Sanda tí won fi èsùn kàn wípé ó gún oko rè Bilyaminu Bello tí ó jé omo alága egbé PDP télè, Haliru Bello pa ní ilé won ní Abuja ní ojó àìkú (Sunday) tí ó kojá, ni won ti gbé lo sí ilé ejó ....
View ArticleOdóbìnrin àgùnbánirò tí ó jé omo odún mérìnlélógún (24), ni won sin ní ìpínlè...
Ojó díè séyìn ni won pín ìròyìn burúkú tí ó selè sí omo odún mérìnlélógún yí tí ó jé àgùnbánirò, tí a mò sí Miss Chinda Uchechi Happiness, ni ó pàdánù èmí rè ní ojó kokàndílógún osù kokànlá (November...
View ArticleOkò tí ó gbé epo petiírólù àti okò èrò ni ó kolu ara won ní Orlu Imo, ogbòn...
Ìjàmbá nlá ni ó selè ní orí afárá (bridge) tí ó gbajúgbajà ní Njaba lónà Umuaka – Okwudor ní ìpínlè Imo. Gégé bí ìròyìn se so okò epo petiírólù àti ti gáàsì tí ó kolu bóòsì elérò méjìdínlógún ní Orlu,...
View ArticleJude Okoye tí ó jé ègbón àwon psquare ti rò wípé àsìkò ti tó kí òun sòrò lórí...
Ó ti dá àwon olólùfé won lóhùn lórí èro ayélujára (Instagram), Jude Okoye ti fi ogbón sòrò nípa aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè tí ó sí wípé òun kó ni olórí ebí won. Ó ko síbè wípé. “A le fi tipátipá...
View ArticleÈmi ni mo ko àkosílè orin tí Davido sèsè ko tí ó n jé “like that” Teni tí ó...
Olórin kan ní orílè èdè Nàìjíríà adá ni lára yá Teni ti pin sí orí èro ayárabíàsá (Twitter) láti fi hàn wípé òun ni òun ko àkosílè Orin tí gbajúgbajà olórin Davido sèsè ko, ó ní òun ni òun ko...
View ArticleArábìnrin tí ó n gba ààwè funfun fún Wizkid láti ségun àwon òtá rè.
Odóbìnrin kan ní orílè èdè Nàíjíríà, Bosslady ni orúko rè n jé ní orí èro ayélujára (Instagram) ti jé kí ó di mímò wípé òun n gba ààwè funfun fún Wizkid, nítorí bí ó se so ó ní Wizkid ní òtá tí ó pò...
View Article