Atitare/Itare: Pataki ewe towa ninu aworan yi ninu odu ifa OTURA ORILANA
Aku ise ana o oni a sanwa o, aanu olorun Olodumare koni fiwa sile loni o ase. Laaro yi mofe ki e mo Pataki ewe towa ninu aworan yi ninu odu ifa OTURA ORILANA, ati iwulo e ti o se je ikan gbogi lara ewe...
View ArticleEwe Yi Je Òkan Lara Awon Ewe Ifa To Dara Pupo
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin ku isimi opin ose, emin wa yio se pupo re laye ase. Laaro yi mofe ki a mo iwulo ewe to wa ninu aworan yi lati inu odu mimo eji elemere(irete...
View ArticleOtura Oriko, wa lo ree silekun ire temi fun mi! Aase!
Hoje também é dia de propiciarmos Olokun. Que a força e o Ase de Olokun abra as portas do progresso e da prosperidade a nossa família criando condições para que todos os obstáculos sejam retirados de...
View ArticleIsu Oro bale ro pee…
A da fun eji, ti o ma bowo fun iko Odidere, won ni ko kara nile, Ebo ni ko mu se. Ojo o ni ro ko pa ina iko Odidere, Iko Odidere d’Orisa. Ni Agbara Olodumare ati oruko Orunmila, Gbogbo ilara, ote,...
View ArticleAPINTANBI
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun Ku isimi opin ose eledumare koni jeki a fi eleyi se asemo o ase. Laaro yi mo fe so die nipa oro APINTANBI ti awon opuro ati alainimo babalawo...
View ArticleOse tu’a
ko-mi-koro awo Ewi l’Addo Orun koko-ko awo Ijesa m’Okun Alakan nigbo ‘do t’eye ifá kerekere-kere adi’a fun Igba Irunmole ajikotun obu okan fun Igba Imole ajikosi alukin fun Orunmila nijo ti won ti...
View ArticleIsebo ni isegun baa ti waye pa a ri, la a
ri ………Ohun gbogbo lowo ori eni. Ori mi ma pada leyin mi. Ojumo Ire o!
View ArticleOdo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Toni Ti Lo
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wi pe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E wa nkan f’idi le...
View ArticleIwure Ojo Eti
Moki gbogbo ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ile nla wayi o Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA OO.) (.Ilosiwaju Ishese Lo Jemi Lo Gun o.) Mofi asikoyi gba ni iwure fun gbogbo eda omo adariwuhun tioba lefi...
View ArticleEjowo O Eyin Ojogbon!! Efun Wa Ni Imoran Lori Ala Yi O
Aki gbogbo eyin ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ILE NLA I.K.O. nla wayi o Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA.) Iye eni kokan wa koni ra ooo Ejowo ooo Ti obinrin basun tioba la ala wipe ohun pade were loju orun...
View ArticleEkale ooo!!! Kin ni oruko ti a n’pe iwu ilu yi ni ile Yoruba?
Gbogbo eyin apapo olorire lagbaiye mini ile nla I.K.O. NLA wayi o lawujo apapo awon ojogbon awo mimo Fun idanileko Lori ASA ile wa Opolo eni kokan wa koni di oku o Ifa koni kuru lakaye eni kokan wa o...
View ArticleEkaaro eyin eniyan mi, aojiire bi?
Eku ise ana o, a si ku popo sinsin odun o emin wa yio se pupo loke erupe ninu alaafia ara o, bi a se njade lo loni eledumare ninu aanu re yio fi iso ati aabo re bowa lowo ibikibi yio wu ko fe sele loni...
View ArticleFi odu ifa mimo OTURUPONDI dupe oore lowo Olodumare
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku odun aku iyedun emin wa yio se pupo re laye ninu ola ati alaafia ara o ase. Mo se ni iwure laaro yi wipe gbogbo ohun ti a lelele lodun to koja lo ti owo wa ko to...
View ArticleE gbo oro Olodumare ninu odu mimo ti Orunmila,
E jiire eyin eeyan mi, e je ki a gbo oro Olodumare ninu odu mimo ti Orunmila, mo nki lati inu Ogbe ‘gunda (Ogbeyonu ), o ki bayi pe,’ Bibi inu ko da nkan, suuru ni baba Iwa, agba to ni suuru, ohun...
View ArticleOrunmila Ni Olugbala Eda, Bee Naa Lo Si Tun Je Olugbala Fun Awon Irunmole...
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Oni a san wa o, bi a se njade lo loni aanu eledumare koni fiwa sile o ase. Loni mofe ki e mo dajudaju wipe Orunmila ni olugbala eda, paapajulo awa adulawo bee naa lo...
View ArticleOrunmila soro nipa ikin ifa !
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o a sin ku isimi opin ose, bi a se nwonu aye loni ako ni pare maye lara o ase. Laaro yi mo fe fi akoko yi fesi si ibeere awon eniyan mi, ti ibeere naa lo...
View Article