Idile Alayo Toni – 17.09.2016 (E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo)
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku aseku odun emi wa yoo se pupo re laye, layo ati ni alafia ara. Mo si ki awa ololufe eto yi, wi pe e ku abo sori eto wa, eto yin,...
View ArticleYoruba Bo Won Ni Agbomojo Lomo N Moju…
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Ido Alayo ti ose yi. E wa nkan f’idi le...
View ArticleOdu Ifa Iwure Toni Ki Bayi Wipe…
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a sanwa sire gbogbo o ase. Odu ifa iwure toni ki bayi wipe: Òkan fìkìkìkì babalawo oladeji difa fun oladeji eyiti won nfojojumo njuwe re fun iku,...
View ArticleOgulutu Oro Toni – 11.09.2016
Hummmmmm ile eni lati nje ekute oni dodo, Morojo oko re feni kankan mo Tori Kosi bi tise o si oni kaluku naa nfaso bo tie ni wara o si loni, wara nbo lola Woo Orewa Kosokunrin tope nile aiye kaluku naa...
View ArticleIpade! Ipade! Ipade!
“Mo se ileri fun orisun mi Ti I se ile yoruba, Lati je omo yoruba atata nileloko, Ati lati je omo oko, Ti ki I f’owo osi Juwe ile baba re, Lati gbe ise, asa Ati ede yoruba laruge, Nibi gbogbo, ati kari...
View ArticleOdo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E wa nkan f’idi le...
View ArticleOdu Ifa Iwure Ti Aaro Yi Ki Bayi Wipe
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tu ku imura toni eledumare koni jeki won gberu ibanuje wa kawa mole loni o ase. Odu ifa iwure ti aaro yi ki bayi wipe: Oseka ori odi a ki nleri...
View ArticleOri mi segbe leyin mi ooo..
Ori eni lawure eni ni, Ori mi segbe leyin mi ooo. Ori a gbe wa o.Ase oo
View ArticleAyeye Ojoibi Toni: Babami Oloye Olatbosun Oladapo
Ododun larorogbo Ododun lari awusa Ododun lati mo obi lori ate Ododun ni sapo nruwe Ododun ni peregun yio Ododun leo ma bee ninu ola ati Alaafia Alekun ogbon Alekun Oye Alekun IMO Alekun emi gigun...
View ArticleOdu Ifa Iwure Toni Ki Bayi Wipe..
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Eku ojo meta o, Ogun lakaye yio bawa segun awon ota wa yio si lana ire gbogbo funwa loni ase. Odu ifa iwure toni ki bayi wipe: Irete Osa kubu irete Osa kebe, irete...
View ArticleIwure to Ori (for Good Luck)
Ka ji ni kutukutu Ka mu ohun ipin ko’pin d’Ifa fun Olomo-ajiba’re-pade Emi ni mo ji ni kutukutu ti mo f’ohun ipin ko’pin Emi ni mo ba ire pade l’ola Translation To wake up early morning And give...
View ArticleOlojo Ibi Toni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Princess Oluwakemi Morenikeji Idowu ti won je okan pataki ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia ara...
View ArticleIwure Ojo Aje 3/10/2016
Ekaro oo se dara dara laji lowuro eni o gege bi emi na se ji oo toba ribee ejekia dupe lowo olodumare kiafi okan kan dupe lowo eleda wa ejekia bo si iwaju oke ipori wa pelu obi tabi eyi tinje orogbo...
View ArticleIwure Osu Tuntun 10/2016
Moki gbogbo ojogbon awo mimo lapapo lagbaiye ninu ile nla I.K.O. Nla wayi oo Wipe :- (.Kinnihun orunmila .O) (ilosiwaju ishese lo jemi lo gun o) (…. Ema wi tele mi wipe ….) Osu yi asan mi sowo Asan mi...
View ArticleAki Ijo Kinnihun Orunmila
(Atorieni Tikosun wonSe) TI ILU IBADAN LAPAPO OOO Aki gbogbo ojogbon awo mimo lapapo lagbaiye ninu ile nla I.K.O. nla wayi oo Wipe :- (KINNIHUN ORUNMILA O) (ilosiwaju ishese lo jemi lo gun o) Aki...
View Article#Opele- Ifa ni…
Ifa ni: Opele lo yo tan lo dakun de’le A difa fun peregede tii se Yeye Ojumomo. Ojumo to mo wa loni ojumo ire ni Peregede! Ifa iwo ni Yeye Ojumomo Ojumo to mo wa loni ojumo Ajé ni Peregede Ifa iwo ni...
View Article