Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live

Odu ifa IWORI MEJI

| | | |  |    |  |    | | | | |  Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi opin ose, emin wa yio se pupo re laye ase. Odu ifa IWORI MEJI lo gate laaro yi, ifa yi gba akapo ti o ba jade si niyanju...

View Article


Òrúnmìla ni Baba wa o e, àwa kò ni Oba méjì, Ifá to Oba o, Òrúnmìlà ni Baba...

Oriki  to Orunmila Ifá Olókun, A – sorò – dayò, Elérìn-ìpin, Ibìkejì Èdùmàrè. The Diviner of the Sea, the one who makes affairs prosper, Witness to Creation, Second to the Creator. Òrúnmìla ni Baba wa...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

ARUGBA is no longer a Virgin maid

Arugba is not only seen as a virgin maid any longer, she is regarded a goddess herself and people make prayers and cast all their problem on her as she bears the calabash and passes on to lead the...

View Article

Ogboni – Isese Lagba

EEPA MOLE !!!

View Article

‪#‎Òmìnira‬

  Òmìnira ṣe pàtàkì, Òmìnira ṣe koko fún gbogbo ohun Òlódùmarè dá, Bí ènìyàn bá nínú ìnira tàbí ìgbèkùn, Tí ó wá rí ìtúsílẹ̀, Àyípadà rere a dé, Ìfọ̀kàbalẹ̀ á wà, A bọ lọ́wọ́ ìdarí ọ̀gá, A bọ nínú...

View Article


Ìfẹ́ –Èyí wa fín àwọn olólùfẹ́ láti fi ranse sí olólùfẹ́ wọn

Ẹyín féràn ẹnu,ofi ṣe ilé, Irun féràn orí ,ofi ṣe ilé, Ìràwò òwúrò tèmi nìkan, Olólùfẹ́ mi, Nínú aba ayé yìí Ẹkuro emi mi alabaku ẹwa rẹ, Ọrọ ìfẹ́ yi n yimi Mo ni mi o nífẹ̀ẹ́ mon, Ife ìwọ olólùfẹ́...

View Article

Aṣọ wíwọ̀

Èèyàn lèyí ni àbí wèrè? Asínwín lèyí ni àbí abugije? Ṣé aṣọ lèyí abi kini? Ha! Ayé tí bàjé, Gbogbo ọmọ adáríhunrun tí sọ àṣà nù, A gbé òmíràn, A fi aṣọ sílè láìwọ̀, A sọ ìhòòhò rí rìn di ohun gidi, A...

View Article

Ìtẹ́lọ́rùn – #Ìtẹ́lọ́rùnṣepàtàkì.

Ìtẹ́lọ́rùn ni baba ìwà, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe pàtàkì fọ́mọ adamọ, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe kókó, A gbọdọ̀ ni ìtẹ́lọ́rùn, Kí a le rí ayé gbé, Kí a le gbáyé ìrọ̀rùn, Aìní ni ìtẹ́lọ́rùn le mú ni jalè, Bí ohun tí a ni kò bá...

View Article


Ìfẹ́ láàárín ara wa

Ìfẹ́ láàrin ara wa Ìfẹ́ dára, Ìfẹ́ dùn bí a bá pàdé oní tí wá, Ìfẹ́ jẹ́ òhun tí ó má ń ṣẹlẹ̀ láàrin àwọn ènìyàn, Yálà ọkùnrin sí obìnrin, Obìnrin sí ọkùnrin, Ìyá sí ọmọ, Bàbá sí ọmọ, Ọkọ sí ìyàwó, Ìlú...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Oríkì Ẹ̀rìn Òsun

Ẹ̀rìn moje ọmọ saaja, Ọmọ eléwé ladogba òróró maro, Ẹ̀rìn wagunwagun Ewá w’Ẹ̀rìn logun eniti yíò wá Ẹ̀rìn logun kowa àpò ide kolowa ọfà, Bàbá kòníbon ajíperin nílé, karo ń lè mọ wọn lójú ogun ẹni Ẹ̀rìn...

View Article

Odu Ifa Owonrin Meji

| | | | | | | |   |   |   |   | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana, eledumare yio pese fun aini wa loni ase. Odu ifa OWONRIN MEJI lo gate laaro yi, ifa yi fore pupo fun akapo ti odu ifa yi...

View Article

Ifa ni…Mariwo fi’bi faara la ile;

Mariwo fi’bi faara la ile; Awo won ni Ile Ìlalà; A difa fun won ni Ile Ìlalà; Nibi ojumo rere tii mo ni; Ojumo rere lo mo wa loni o. Aase! Ifa says: Mariwo fi’bi faara la ile; The Awo of the town of...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Odu Ifa Ogunda Meji/ Ejioko

 |    | |    | |    | | |  | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana, bi ile oni se mo ao ri tiwa se ise wa yio si ni ibunkun lori ase. Odu ifa OGUNDA MEJI/EJIOKO lo gate laaro yi, ifa yi gba...

View Article


#Osunisholy

Ologbo se oro okije aresa se oro okije ase ije osun osogbo ni oni yi o emafi osun se ibaje eyin eni yan ibi ema ba olosun je osun ki se ote osun ki se ibaje tori idi eyi olosun ki lu jibiti ni agbara...

View Article

Ogulutu Oro Toni – 27.08.2016

Hummm bona kan o badi odamiloju pe ona Miran olela,iyen fun enito ba mo nkan ti nse. Woo Orewa Benikan ba sope sise re titan lodo ohun, mofe komope ose tie ni kose ti Olohun o, nise ni kode fila mowobe...

View Article


Odu Ifa Osa Meji

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi opin ose, adura wa yio gba o. Odu ifa OSA MEJI lo gate laaro yi, ifa yi gba akapo ti odu ifa yi ba jade si niyanju wipe ki o sora gidigidi fun oore sise,...

View Article

Odu Ifa Irosun Meji

 |    |  |    | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, gbogbo ojo aye wa yio maa dara si lojojumo ni o ase. Odu ifa IROSUN MEJI lo gate laaro yi, ifa yi gba akapo ti odu ifa...

View Article


Ifá ni Òtítọ́! (Ifá é Verdade)

Por Mario Filho Àbọrú, Àbọyè o! Em um verso do Odù Ọ̀sá Òtúrá Ifá diz (já traduzido): Ọ̀sá Aláwo pergunta: “o que é verdade?” Eu também pergunto: “o que é verdade?” A verdade é o Olúwo do céu [mundo...

View Article

May the Eleye birds not have a craving for our intestines.

Ase   Photo Cc – Moyo Okediji‎

View Article

Odu Ifa Oturupon Meji/ Ologbon Meji

| | | | | | | |  |    | | | | | Ekaale  eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise oni o, esu odara yio gbare ibunkun lopolopo fun wa loni o ase. Odu ifa OTURUPON MEJI/OLOGBON MEJI lo gate laaro yi, ifa yi...

View Article
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live