Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live

Eeto Owe L’esin Oro

YAKUB BUKKY – Nje a tun ti de loni gegebi ise wa ni gbogbo ojoru. Oro enikokan wa koni dojuru oo (amin), a ki gbogbo kaabo si akootun eeto yin, eeto wa owe l’esin oro, oro l’esin owe, ti oro ba sonu,...

View Article


Idile Alayo: E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo

Mo ki gbogbo wa pata lokunrin ati lobinrin, lomode ati lagba wipe a ku ise oni, a si ku abo sori eto wa eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. E wa nkan fidile tabi ki e gbiyanju fidile nkan, ki a jo...

View Article


Arun Karun Konifile Awa Se Ibugbe o

Eyin tiaa..akuu gbalegbata oni o…arun karun konifile awa se ibugbe o. Ase..Paronure lawaa..Se e gbagbe pe lati onilo di ola.faaji nson. Leyin Elere ti okan yin yan laayo. Pe kowa kolu siwa nibadi. Emaa...

View Article

Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo

Mo ki gbogbo wa pata lokunrin ati lobinrin, lomode ati lagba wipe a ku ise oni, a si ku abo sori eto wa eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E wa nkan fidile tabi ki e gbiyanju fidile nkan, ki a jo gbadun...

View Article

Eto Olobe Loloko Sokoyokoto Toni

Olorun ogo ni fun oruko re, oba to ni kokoro Iku ati iye lowo, oba ti o le pa, oba ti o le ji, adupe lowo eledua, oba ti o fi aanu re pawa mo. “FURAIDI IRESI” (fried rice) ni ounje aladun ti a o fi ko...

View Article


Olojo ibi Toni

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa MONSURAT KEHINDE ADENEKAN ALANI ti won je okan pataki ninu ebi Omo Oodua Rere. Maami olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia...

View Article

Ojumo Ire ni

Ile to mo wa loni, ka ma subu ka ma feyin owo danu,toripe ojumo ire ni, ka ma ko elenini ka ma ko agbako toripe ojumo ire ni,ori owo Lori wa loni, ESE aje lese wa lonj aji lowuro ati ba eleda soro wipe...

View Article

Iwure Owuro – 05.07.2016

E MAA WI TELE MI : …….. *Edumare ma se je ki n fi ota s’ore. *Oluwa gba mi lowo afoju-feni ma fokan-feni. *Edumare gbe mi leke abinu eni. *Oluwa ma se je ki n je egungun kehin eran. *Edumare ma se je...

View Article


Ogulutu Oro Toni

Igbiyanju loma ngbeni de ipo ola Igbiyanju loma njeki kadara o se # wo Oremi masinmi igbiyanju oo ki o le dele ileri Majeki isoro kisoro kopa okanre da Lori ipinu ayo re Tepa mose re loni Ki osi mo wo...

View Article


Tani arakunrin-olokada yi jo ?

Kabiesi re Edua! a se otito ni oro awon agba to sope mejimeji ni Eledua da eniyan. OUN TO BA JO(resemble) OUN LA FI WE ARAWON EPO-EPA JO POSI ELIRI OWO-ALABAUN JO HANHAN-OPE. tani arakunrin-olokada yi...

View Article

Sun re o: Francis Aiyegbeni alase ‘D’Rovans Hotel’ ni ibadan

ojuluoooooooo! owe ni oro-aye, A NLO SI OYO O KOJU SI OYO A TUN BO LATI OYO OYO NAN LO TUN KOJU SI. SE BI ILU-GANGAN. iyen nipe ORUN LATI WA ORUN NAN LAO PADA SI. iku pa ABIRI o ti re orun-alakeji sun...

View Article

Iwure Owuro: 08.05.2016

E MAA WI TELE MI : …….. *Oluwa gba eru iya lori mi. *Edumare ma se je ki n seru egbe. *Oluwa taari alaanu si mi. *Edumare fiso re so mi. *Oluwa pase irorun sinu aye mi. *Iku aitojo ko ni pa mi(Ase)....

View Article

Iki’Ni Fun Ayeye Ojo Awon Iya Wa

ORIN : “E bami KIRA fun ‪#‎Mama‬ mi.. ‪#‎Orisa‬ bi #IYA o.. Ko si Laye… …………….. Iya mi.. Abiyamo lojo Ogun le.. Abiyamo Oloja Aran Abiyamo tii fojooumo wa ko le Dara fun Omo… …………………… Ki Emi gbogbo...

View Article


Ogulutu Oro Toni: 08.05.2016

Hummm wo oremi banuso mobayan so tori inu jin. # wo Opolopo ore lo nfara han gegebi ota Oplopo ota naa losi nfi ara han gegebi ore….. # nje Otie mo pe opo alangba lo dankun dele ao kuku mo eyiti inu...

View Article

Aku ojumo lokun !

Lobinrin wa se dada laji bii.. Adupe lowo OLODUMARE too mu emi ati iwo losii ipo oku lati ano too tun jiwa pada saiye, si aye rere nitori gbogbo eni bati sun ti oku ope ni fun ODUMARE.. Moo wa nfi...

View Article


Iwure Owuro: 14-05-2016

E MAA WI TELE MI : ….. *Fitila ogo mi ko ni ku. *Aso iponju ko ni se dede orun mi. *Oluwa ba mi segun ota ile. *Edumare ba mi segun ota ode. *Ina omo ko ni jo mi. *Ina Aya/Oko ko ni jo mi. *Oluwa mu mi...

View Article

Arewa Asa Toni: Afeez ati Mide Martinez Abiodun

Ko so’ogun mo bee si ni ko so’ote mo ni igbeyawo eleyi ti o ku die ko dojubole. Oserekunrin Afeez Abiodun “Afeez Owo” ati iyawo re Oserebinrin Mide Martin ni ti mu ife won padabo sipo. Laipe yi ni...

View Article


Ibeere Toni: 15.05.2016

Nje Iwo leso “FACEBOOK PASSWORD” re fun Ololufere????? Huuum ema paro ooo

View Article

Oro ton’lo Lowo bayi: E wo tomato timo ra ni 500 naira

Eku Dede asiko yio eyin eniyan Atata tin GBE inu ilu Yoruba Atata, oro tonlo Lowo bayi ni mo muwa oro elo obe to won gogo yi ma ni mofe kia soro Lorie o. E wo tomato timo ra ni 500 naira, egbo na o se...

View Article

Oruko Kan Fun Iya omode yii ?

Eyin Eniyan mi Eje Kia Rerin die. Oruko kan fun iya omode yii ?

View Article
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live