Idile Alayo: Oro owun si fe toju sumi
A ki gbogbo wa ku jimo oloyin toni a si ki wa ku abo sori eto Idile Alayo ti ose yi, gege bi ise wa atejise kan ti a ri gba lati owo okan lara won ololufe eto yi ni a o maa ka si wa leti loni, ki a jo...
View ArticleIwure Owuro 02-04-2016
E MAA WI TELE MI : ……. *Edumare ma je ki n soore daran. *Oluwa ma je ki n gbalejo oran. *Edumare ba mi segun elenini. *Oluwa ran alaanu si mi. *Edumare gba mi lowo alaroka. *Oluwa dakun rojo ibukun...
View ArticleOunje Emi Fun T’ooro Yii (02-04-2016)
………………………………………………………. Iwe-Iroyin #AYEKOOTO_MAGAZINE fun T’osu kerin ti jade sita bayii, #Ogorun naira #100 ni beere fun tire lodo #VENDOR nibi-kibi …………………………………………………………… AMOYE TONII :...
View ArticleIroyin Ere Idaraya Lerefee (02-04-2016)
Ajo to n mojuto #LEAGUE awon obinrin nile wa “NWFL kede ola ojo keji osu kerin gege bi ojo ti idije boolu LEAGUE obinrin fun saa tuntun yoo gberaso kaakiri ile wa. ……….. Emi ati awon agbaboolu mi...
View ArticleArewa Asa Toni: Adekunle Kosoko (Gold)
Arewa asa toni ni olorin taka sufe (hip hop) ti gbogbo wa mosi ADEKUNLE GOLD, Won je omo bibi ilu Eko ni idile oba kosoko, ti wonsi jade nilewe gbogbo nise (polytechnic) towa nilu Eko enitoje awokose...
View ArticleAwon Tia N’Ibadan
Ibadan mesi Ogo, Nile Oluyole, Ilu Ogunmola, Olodogbo keri loju ogun, Ilu Ibikunle alagbala jaya-jaya, Ilu Ajayi o gbori Efon se filafila. Ilu Latosa Aare-ona kakanfo, Ibadan Omo ajoro sun, Omo a je...
View ArticleEba Wa Da Si Oro Yii ooo
Eyin Okurin Se ele gba wipe ki Iyawo yin je oga yin ni ibi ise ?
View ArticleEwi Toni – 09-04-2016
Bisu eni ba ta Ka fowo booje lo to Agba ofifo ni dun koro koro Mo ti reru to domo Mo si ti riwonfa to ko peteesi Igba o lo bi orere Owo aago laye To ba lowaju a tun pada seyin Igba lonigba n ka Ile o...
View ArticleIwure Owuro – 09/04/2016
E MAA WI TELE MI : ………. *Edumare pase irorun sinu aye mi. *Oluwa tanmole si ogo aye mi. *Eni to n se atako ire aye mi, Oluwa f’eje re setutu ola mi. *Oluwa gbe alaanu dide si mi. *Pasan ti aye fi n je...
View ArticleOgulutu Oro Toni
si gbogbo okunrin hummmmm moseba gbogbo obinrin ooooooo………eyi ni oruko meta ti OLOHUN so wipe awon OBINRIN nje ti gbogbo OKUNRIN SI GBODO MO,,, Akoko:AWAWU Ekeji: ONIGBAGBE ENIYAN Eketa: ONIFENU # wo...
View ArticleWhat Ifa Says in Ogbe Ate
In Ogbe Ate, Ifa says everybody should do Itefa (Ifa initiation) to know one’s mission on earth, one’s destiny and in order to have all good things of life. A ki i ji ni kutukutu/ Ka ma modu to dani...
View ArticleAyo Ab’ara Bintin
Ope ni fun Olorun nitori ti o seun ti anu Re duro laelae. Mo layo lati so fun wa wipe Eledua fi Omobinrin lantalanta da ebi kan pataki ninu ilu yi lola. Tii se ebi Olori AJOKE GOLD OLUWAKEMI ti won je...
View ArticleOlobe Lo Loko Soko-Yokoto
Eto Olobe lo loko soko-yokoto ni o gori afefe bayii,,,,,, Adupe lowo olorun fun abo re lori wa, oba ti o pawa mo titi Di ojo oni, a dagbere ni ijejo, atun dupe wipe eledumare ka wa ye loni. Lori eto...
View ArticleOdo Iwoyi !
A ki gbogbo wa ku ise oni, a si ki wa ku abo sori eto wa eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E dakun e wa nkan fidi le abi ki e fi idi le nkan, ki a le jo gbadun ara wa loni. Eto wa ti ose yi yoo yato...
View ArticleOjuitere !
ojuitere, iba re’oo baba IFAYEMI ELEBUBON, iba re’oo baba PETER IFATOMILOLA, iba re’oo baba, ADEBAYO IFALETI, baba wa AWODIRAN AGBOLA baba ADEGBOYEGA OMO ODO AGBA, awon agba onifa ti won gbo n’ti ifa...
View ArticleIwure Owuro Toni: 17-04-2016
E MAA WI TELE MI : …… *Adun, ayo, idunnu ni temi titi aye *Ire owo, ire omo, ire aiku ni temi. *Apari inu mi ko ni ba tode mi je. *Orisun ayo mi ko ni gbe. *Ise mi ko ni dojuru. *Eledua tete ran...
View ArticleArewa Asa Toni: 17-04-2016 Ogbeni/Alaji Taiwo Hassan (Ogogo)
Arewa asa wa toni ni Alhaji Taiwo Hassan, abi won ni Ilaro ni odun 1959, baba tobi won ibeji ni, baba tobi baba won ibeji ni, emerin ototo ni won ti bi ibeji ninu ile won, Won losi ile-we alakobere...
View ArticleArewa Asa Toni
FEMI ADEBAYO ODUNLADE ADEKOLA Taloye kogba eni ti o dara ju ninu awon osere meji yii ?
View Article