Quantcast
Channel: Àṣà Oòduà Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Awon ojogbon fi oye dokita da Tinubu lola

Oloye agba egbe APC, Asiwaju Ahamed Bola Tinubu ni won ti foye dokita dalola bayii ni ogba Yunifasiti tiluu Abuja. Idalola agba oloselu to je gomina ti yoo je sikejila (12th) nipinle Eko lo waye ninu...

View Article


Iyanu ti sele nipa awon omo Babington Ikorodu ti won jigbe

Ni ojo Aje to koja yii (29/02/15) ni awon ajinigbe kan yawo ileewe Babington Macaulay ‎Junior Seminary School to kale si agbegbe Ikorodu nipinle Eko ti won si ji awon omo obirin akekoo meta salo...

View Article


“Awon soja yin mi ni bajinatu, won fe pami”– Olu Falae

*Awon ika eniyan wo lo wa nidi isele yii? *Se agbanipa ni won tabi awon soja ti won se palapala nigboro? Oloye Olu Falae ni ori ti koyo bayii lowo iku ojiji nigba ti awon soja kan ti enikeni ko mo...

View Article

Owo Jegudujera Abacha: Ile ejo ti fesun kan Obasanjo ati Jonathan

*Won tun ranse si Yar’Adua lode orun wi pe ko wa salaye *Ile ejo ti gbe ise to le fun Aare Buhari lati se Obasanjo, Yar’dua ati Jonathan Kootu ijoba apapo to gaju lo to kale siluu Eko, Federal High...

View Article

Won ti pago lori maanu to fowo kan oyan omoge

Arabirin, Ifeoma Okoroafor, eni odun mejidinlogbon (28), lo ti salaye fun ilejo Upper Area Court to wa niluu Abuja wi pe, Ogbeni Musa Goddy fowo gbe oun loyan jo ni oun se fo nigo lori.  Ogbeni Musa lo...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Femi Adebayo, Funke Akindele, Mercy Aigbe, Toyin Aimakhu nibi ami eye Africa...

Aimoye osere lo peju sibi ami eye (Africa Magic Viewers Choice Awards) 2016 to waye niluu Eko. Eyi to waye yii ni i se elekerin iru e. Oruko awon olubori ami eye naa wa nisale .

View Article

Omidan asewo ti se ‘kerewa’ koja sorun alakeji

Awon Yooba bo, won ni owo tada mo ni kada lehin. Iku ogun ni i pa akikanju, omi ni pada wa pa omuwe lodo. Okan ninu awon omo asewo ilu Abuja ti oruko re n je Omidan Ome Enyi lo ti se agbako iku ojiji...

View Article

Oro Sunku: Ore Mi, Iran Kerin

(Ni nnkan bi aago meje irole ni ibugbe awon obinrin ni ogba Yunifasiti, ero po nibe lokunrin lobinrin. Awon kan n wole, awon kan n jade. Awon okunrin miiran wa ninu oko ayokele pelu awon omoge, won n...

View Article


E jo kilo kun ki arakunrin yi fi si obe yi ko ba le dun dada

Edaku, e fun foto yi ni Oruka kan ?

View Article


Oro Sunku: Ore Mi, Iran Keji

-Sola:. ( O wole, o kumle si egbe ibusun Baba ati Iya re) E jowo, mo nilo owo nile eko ni. Won fun wa ni ise asatilewa kan ni, yoo si na mi to egberun marun naira. -Baba Sola:. Ha! Egberun marun ke?...

View Article

Oro Sunuku

Moki gbogbo wa ku ise oni, asejere ni gbogbo wa yoo se lagbara Eledua ase. Eyi ni lati fi to gbogbo a wa ololufe eto yii leti wipe, gbakogbi itan akakogbon ti a npo po ti di itan agbeleka fun gbogbo wa...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Nje toba jepe Eyin Ni arakunrin yi

Kilerope Elese Fun Iru nusi bayi ?

View Article

Ajisa lori eto Gbajumo Osere

View Article


Ara lori eto Gbajumo Osere

View Article

Biodun Okeowo lori eto Gbajumo Osere

View Article


Sunkanmi lori eto Gbajumo Osere

View Article

Ifankaleluya lori eto Gbajumo Osere

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

ibere ranpe daruko awon nkan meji yi ati wipe awon wo ni won nlo ?

jowo fi idahun re sowo si mi ti o ba je ojulowo omo yoruba

View Article

GBEJÉÉ KIO NIYI

Éni Aye nyé loni, Kio dakun kio se araré jéjé, Éni Igba sii ndun fun, Kio jare Kio fi araré siwon. Ile-aye Kii se Awailo ilu rara. Olódùmarè Nikan ni aremabo. Ômô ti Abi Loni, ti osi di Éni A Njiké,...

View Article

Owe Toni: Pari owe yi

1.Awolu mate e????? 2.Enitio dasofun ni??????

View Article
Browsing all 1429 articles
Browse latest View live