Eku Dede Asiko Yi Ni Gbogbo Ibi Ta A’Ba Wa o
Oruko mi ni TINUKE mofe ki eyin omo ilu yi gbami ni yanju lori oro yi ni ooooo Lati bi osu marun se yin ni ago ibani soro kan man pe mi Ti eni yen ba pe mi EPE nla Loman se funmi. Ti moba pe pada EPE...
View ArticleArticle 5
Enikan lo lo ki ore re,ko si ba ore re nile, sugbon o ba okan ninu awon omo ore re nile. Oni baba re n ko? Omo naa ni:”Baba mi lo so okun (rope) aye ti o fe ja” Iya re naa n ko? Omo naa ni:”Iya mi wa...
View ArticleEyin ojogbon eniyan, kini itumo awon oro won yii ?
Enikan lo lo ki ore re,ko si ba ore re nile, sugbon o ba okan ninu awon omo ore re nile. Oni baba re n ko? Omo naa ni:”Baba mi lo so okun (rope) aye ti o fe ja” Iya re naa n ko? Omo naa ni:”Iya mi wa...
View ArticleOsatura ni kini otito ?
Emi ni ki ni otito ? Orunmila ni otito ni oluwa orun to nto aiye Ogbon ti eledumare nlo Ogbon – nla, opolopo ogbon Osatura ni kini otito ? Emi ni ki ni otito? Orunmila ni otito ni iwa eledumare Otito...
View ArticleSisi ologe elo ni Suru ooo
Se Eledumare to da IDI yin bi o se mon IDI kaluku yin se ko se da ni in? Awon kan wa sese ma lo ogun abi abere. Se ni tori iranu yi na E wo won oooo. Awon kan ni IDI won ti baje yi ooooo Latara pe won...
View ArticleE jowo eyin, abiyamo, e dakun e gba wa ni imoran ..
OOOOOOO Oro naa ti di lbanuje ati edun okan fun molebi mi, e dakun e gba mi ooooo. Mo je Omo odun metadinlogbon (27 years) Taiwo. . . . . . ni Oruko mi, Okunrin ni mi, bakan naa ni ekeji mi naa n je...
View ArticleIwosan ogbe inu
Awon nnkan won yii lo maa n se okunfa ogbe inu; ki eniyan maa fi ebi pa ara re nigba gbogbo, jije ounje gbigbona ati iyo pupo ninu ounje ati bee bee lo. Bi a se maa se iwosan naa ni yii: A ma wa ogede...
View ArticleKini okunrin le se to le mu iyawo re se iru idajo bayii fun
Omobirin yii lo fi ja nnkan omokunrin oko re sonu patapata.
View ArticleEwu to wa ninu foonu lilo ati pataki ilera wa
Opolopo wa ni a n lo foonu ni aye ode oni, sugbon ti a kosi mo awon ewu keekeke to ro mo o eleyii to le se ipalara fun ago ara wa. E je ka ri daju wi pe a n nu foonu wa lorekoore. Paapaa julo, ti a ba...
View ArticleBayii ni a se le se iwosan fun eni to ni kokoro inu eje
Awon ohun elo ti a gbodo wa ni yii: 1 Omi osan wewe igo kan tabi oti igo kan tabi omi grape igo kan 2 Capsule red & yellow eyo mewaa (10 pieces) 3 Ewe taba ti won ti lo, sibi imuko kan pere Bi...
View Article“Ijoba etan ati jaguda ni Mimiko n se nipinle Ondo” – APC
*Mimiko ya bilionu meedogun soto lati san gbese Lose to koja ni awuyewuye kan tun seyo nipinle Ondo nigba ti egbe oselu APC tako Gomina Olusegun Mimiko ti ipinle naa nipa bo se ya bilionu meedogun ati...
View Article